Midnight Crew - Mo Dibo fun Jesu Songtexte

Songtexte Mo Dibo fun Jesu - Midnight Crew




Eyi ni eri ife Oluwa si mi,
Mo gbe igbese pataki mo se gbeyawo
Lai pe ojo moye moferaku
Ao bati gbe mi gbin Oluwa ni o je
Alleluya, Ogo ni fun baba
Ma fijo iyin yin Olorun wa
Alaye ni o yin o bo ti ye
Alleluya foba onibu ore
Mo dibo fun Jesu
Jesu gba akoso aye mi dara o
Mo dibo fun Jesu





Attention! Feel free to leave feedback.