9ice - Arami Lyrics

Lyrics Arami - 9ice



Mi lẹ... mi lẹ
Òní lẹ'... Mi lẹ'
Kudira ti ba ni oya, ko bami gbe, gbe
Eruu ni ile aiye yii, o ni ohun mo fe fi se
You gat to let it vibrate, let it vibrate for me
Gbe su'mo mi, Ara ki sa f' ara oooo
O yẹ ye
Arami ń bẹ lọ'nà yeeeeh
Arami ń bẹ lọ'nà eeh
Arami ń bẹ lọ'nà yeeeeh
Arami ń bẹ lọ'nà eeh
Ara mi ń bẹ lọ'nà my dear ooh
Arami ń bẹ lọ'nà eeh
Arami ń bẹ lọ'nà Kudira
Arami mi ń bẹ lọ'nà yeeeh
Hmm hmm hmm
Jẹ' n gbó ṣe rẹ mama ó ooo
I go take it easy on you jọ'wọ' máa pariwo
Adigun ńlá ńlá
Adigun baálé ooo
Torí mo dangajia
ti mo mi ládùúgbò èéh oo
You gat to let it vibrate, let it vibrate for me
Gbe su'mo mi, Ara ki sa f' ara oooo
O yẹ ye
Arami ń bẹ lọ'nà yeeeeh
Arami ń bẹ lọ'nà eeh
Arami ń bẹ lọ'nà yeeeeh
Arami ń bẹ lọ'nà eeh
Ara mi ń bẹ lọ'nà my dear ooh
Arami ń bẹ lọ'nà Kudira
Arami mi ń bẹ lọ'nà yeeeh
Jẹ ń gbọ' ṣe yẹn
Jẹ' ń ìṣe yẹn
Ọmọ gbọ' ṣe yẹn
Jẹ' ìṣe yẹn
Ọmọ jẹ ń ìṣe yẹn
Ọmọ jẹ ń ìṣe yẹn
n wọ 'bi 'ṣe yẹn
Jẹ' ń ìṣe yẹn
Ọmọ gbọ' ṣe yẹn
Jẹ' ìṣe yẹn
Ọmọ jẹ ń ìṣe yẹn
Ọmọ jẹ ń ìṣe yẹn
n wọ 'bi 'ṣe yẹn
Yeeeeh eeeeeh
O le tún gbobe eeeeh
Fún wo dééeee èéh
Yeeeh yeeh ooh ooh
Arami ń bẹ lọ'nà yeeeeh
Arami... Arami
Arami ń bẹ lọ'nà eeh
Arami ń bẹ lọ'nà yeeeeh
Arami ń bẹ lọ'nà eeh
Ara mi ń bẹ lọ'nà my dear ooh
Arami ń bẹ lọ'nà Kudira
Arami mi ń bẹ lọ'nà yeeeh
Arami ń bẹ lọ'nà eeeh
Arami ń bẹ lọ'nà eeeh
Eeeh
Olumix
Yeeeh èéh Arami ń bẹ lọ'nà eeh




9ice - Classic 50 Songs
Album Classic 50 Songs
date of release
30-01-2019




Attention! Feel free to leave feedback.