9ice - Otami Lyrics

Lyrics Otami - 9ice



(It's Protunez on the beat)
Ẹbilà, ẹbilà
yàgò, yàgò
Ọmọ olóore dé, lọ
Ìya to jẹ o, o gbọdọ jẹ gbé
Òṣì to o, o gbọdọ gbé
Ìya to jẹ o, o gbọdọ jẹ gbé
Òṣì to o, o gbọdọ gbé
Ẹbilà-àá, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ńbanidárò
Ẹbilà o, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ńbanidárò
Aṣa ń pekéde ẹyẹlé o gbọ o
Ẹyẹlé ń gbọ nisẹ lo ń pi-rọrọ
Wọn p'oto o, lo'to
Wọn k'òtò o, wọn bùsi
Mo sọ fún wọn tẹlẹ-tẹlẹ ẹhìnkulé láṣẹ ń gbé
Inú'lé tẹrí yẹn, lẹni o ń ṣe wa-aah
O fẹ pẹ láyé, ojú o rí, ńkan máa f'ọwọ
Wọn ṣe rí, o lo make e
Wọn gùn rí, o lo lókígbe
Wọn yìn ìbọn fún rí, o lo layetà
Ìwọ dírá, o tẹ tàn nìyẹn, my brother, ah
Ìya to jẹ o, o gbọdọ jẹ gbé
Òṣì to o, o gbọdọ gbé
Ìya to jẹ o, o gbọdọ jẹ gbé
Òṣì to o, o gbọdọ gbé
Ẹbilà-àá, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ńbanidárò
Ẹbilà o, ọtá ilé, ọtá òde dé)
Ámónì ṣe ní, ńbanidárò
Aṣa ń pekéde ẹyẹlé o gbọ o
Ẹyẹlé ń gbọ niṣe lo ń pi-rọrọ
Gbogbo òun tójú kọ lẹnu máa sọ, ọrọ níí
Yára láti gbọ'rọ, lọ'ra láti f'èsì, ọrẹ míì
Wọn ṣọ mí, ọrẹ, jọ, di monitor
Ò lọ school, jọ, ò ńṣe àgùnbanirọ
Nígbà tójú pọn mí, ọrẹ, o mọ ó jìnà gan-
Àwa náà ré, àti gòkè àti sọọ
Àje Ogungun-nisọ otí tàn
Ìgbà kàn nígbà yẹn, àwa janitor
Nísìnyí, ẹni f'ojú àná w'òkú, ẹbọrá áàbolaṣọ-uh-uh
Ìya to jẹ o, o gbọdọ jẹ gbé
Òṣì to o, o gbọdọ gbé
Ìya to jẹ o, o gbọdọ jẹ gbé
Òṣì to o, o gbọdọ gbé
Ẹbilà-àá, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ńbanidárò
Ẹbilà o, ọtá ilé, ọtá òde
Ámónì ṣe ní, ńbanidárò
Aṣa ń pekéde ẹyẹlé o gbọ o
Ẹyẹlé ń gbọ nisẹ lo ń pi-rọrọ



Writer(s): Alexander Abolore Adegbola Akande


9ice - Afro Juju
Album Afro Juju
date of release
17-12-2022




Attention! Feel free to leave feedback.