King Sunny Ade - My Mother Lyrics

Lyrics My Mother - King Sunny Ade



Iya la la bawi omo
Iya la la baro omo
Orisa bi iya kosi laye
Orisa bi iya sowon
Orisa bi iya kosi laye
Orisa bi iya sowon
O gbemi sinu fosu mesan
O ponmi seyin o ju odun meta
Kini n ba je gbagbe mama
Iya o se n paro
Be lomo o se n paro
Omo to ni iya n o da
Omo to ni mama n o mo yi omo
E ba re lowo e
Se o toju mama e dada



Writer(s): King Sunny Adé


King Sunny Ade - E Dide (Get Up)
Album E Dide (Get Up)
date of release
29-07-2008




Attention! Feel free to leave feedback.