9ice - E O Mo Meme paroles de chanson

paroles de chanson E O Mo Meme - 9ice



Uhhh, Ancestor oh
It's Owon on the beat; Owon on the beat oh yea yea-
Momowi samura dobuyeh; iri famuwada
Famuwiyi famuwada (Yeh); iri famuwada
Famuwa famuwada muya; kokuli famuwida
Saliya mukobi, iri famuwida dadia (Iyeh)
Won wa hit, mo n wa ever green (Yeh)
Won wa hit, mo n wa ever green
Won wa mercy, mo n wa blessing (Iyeh)
Won wa favour, na my neighbour
Olorun l'on sogo; Baba mi l'on sola
Olorun n be n'idi aro, ko kuro nibe rara; yeh
E O Mo Meme, ah; E O Mo Meme, yeh
E O Mo Meme, ah; E O Mo Meme, yeh
E O Mo Meme, ah; E O Mo Meme (Iyeh)
Won posh, mo n ke to
Won t'oti, mo n gba'go (Iyeh)
Won rough, mo smooth
Mo n accept, won refuse (Iyeh)
Mo n acquire, won lose
Yeah; Taylor, won l'oju mi gbe
S'e mo nkan t'o ti ri ni?
Won l'ese mi tirin, s'e mo irin t'o ti rin ni?
As a female artiste, s'e mo'ye okunrin t'o fe ruin mi?
Won a ni tin ba le wale won, p'awon le wa lo room mi
Ki lo sonu lowo yin t'e n wa kiri?
Elomi wa lowo, elomi wa la ti wa kiri (Iyeh)
Elomi ma blow gbau, eh, t'o ba korin
Elomi alagbede ni, o wa la ti wa kan irin
Pastor ti so f'elomi pe ise bayi lo ma se
T'o ba ma pari story e, k'o ma lo di 'o ma se' (Iyeh)
O n binu, o n para tori o rowo tunrase; O de ti gbagbe p'awon t'o lowo yen, Olorun lo fun won se
Nkan t'Olorun ko fun e ko lo ko f'emi
Eyin le ma mu'ti, kan po eko f'emi (Iyeh)
Emi le ma korin God de ma fo fun mi
Hit t'on f'ogun odun wa le j'ojo kan f'emi; yeh
Olorun l'on sogo; Baba mi l'on sola
Olorun n be n'idi aro, ko kuro nibe rara, yeh
E O Mo Meme, ah; E O Mo Meme, yeh
E O Mo Meme, ah; E O Mo Meme, yeh
E O Mo Meme, ah; E O Mo Meme (Iyeh)
Olumix on the mix
It's Owon on the mix
(Iyeh)




9ice - Goat
Album Goat
date de sortie
27-03-2018




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.