King Sunny Ade - Prince Adesanya paroles de chanson

paroles de chanson Prince Adesanya - King Sunny Ade



A l'oba lola, alade ni
Pele pele Adesanya
Ade sector oba
Alade alade alade ni e
Alade alade alade ni e
Adesanya omo oloye (alade ni e)
Ade sector (alade ni e)
Eyin ogbagba ti n gba ara ilu o (alade ni e o)
Omo alade l'ade ye
K'ade pe l'ori, ki bata pe l'ese oba omo Adesanya
T'oba ni mo wa ni mo wi (t'oba ni mo wa)
T'oba ni mo wa Adesanya (t'oba ni mo wa)
Mi o yaju s'oba, mi o s'ete s'oba
T'oba ni mo wa mo wi o Adesanya omo oloye o
Omo Adesanya (omo Adesanya o)
Oba to to bi aro (omo Adesanya o)
Baba Justin mi (omo Adesanya o)
Awolarewaju Alumu da n China (omo Adesanya o)
Awo Habib Awobiyemi (omo Adesanya o)
Chattered Accountant Baba ni (omo Adesanya o)
Treasurer and General Secretary (omo Adesanya o)
Kabiesi re (omo Adesanya o)
Oba o Oba o (omo Adesanya o)



Writer(s): Sunny Ade


King Sunny Ade - Isele Yi Leju
Album Isele Yi Leju
date de sortie
05-07-2013




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.