Oba - Akoda paroles de chanson

paroles de chanson Akoda - OBA



Akoda a,baba mi o,aseda a
Gbogbo 'nle Jesse omo alade alafia
Akoda aaa,aseda aaa
Akoda aaa,aseda aaa
Gbogbo 'nle Jesse omo alade alafia
Akod'aiye iba re,ased'aiye iba re o o
Ariiro ala oba ti nje emi ni emi ni ma se beru
Ab'eti lu ka ra bi ajere
Ogbamu gbamu oju orun o maa se e gbamu
Ogbi I gba ti'ngba 'lai lara,a yin o logo o o
Ab'eti lu ka ra bi ajere
(Kabiesi)
Ogbamu gbamu oju orun o se gbaa mu
(Ya a gbo ya a ju okunrin ogun)
Ogbi I gba ti'ngba 'lai lara,a yin o logo o
(Ari I ro ala oba a tanyanyan tanyanyan,eh)
Akoda aaa
(Akoda aiye aseda orun)
Aseda aaa
(Aseda,aweda,amoda,aweda)
Akoda aaa
(Ka a bi yesi okunrin ogun)
Aseda aaa
(Gbogbo 'nle Jesse)
Gbogbo 'nle Jesse omo alade alafia
Akoda a aiye iba re
Aseda a aiye iba re o o
Ari I ro ala oba ti nje emi ni emi ma se e beru
Ab'eti lu kara bi ajere
Ogbamu gbamu oju orun o se e gba mu
Ogbi I gba ti'ngba 'lai lara,ayin o logo o o
Akoda aaa
(Olorun agba 'nla aiye o)
Aseda aaa
(Agbagba mumu,ataba tubu)
Akoda aaa
(Apata 'aiye ra'iye)
Aseda aaa
(You are stronger than the strongest)
Gbogbo 'nle Jesse omo alade alafia
(Wiser than the wisest,greater than the greatest)
Akoda aaa
(Eru jeje ti n migbo kijikiji)
Aseda aaa
(Kiniun eya nla Judah)
Akoda aaa
(Apa nla to so le aiye ro o)
Aseda aaa
(Almighty,all-knowing God)
Gbogbo 'nle Jesse omo alade alafia
Aki I kitan oba to fi mo le bora
(You are the omni-potent)
Aki I kitan oba to fi mo le bora
(The sovereign king)
Aju u ba re o baba
(The Lord of lords)
Aki I kitan oba to fi mo le bora
(The king of kings)
(The centrepiece of civilisation)
(You are the highest personality in the universe)
(King of glory)




Oba - Akoda
Album Akoda
date de sortie
12-01-2011




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.