Midnight Crew - Surulere текст песни

Текст песни Surulere - Midnight Crew



Suurulere o
Aaaaaaaooo
E sun mo 'bi
O ya!
E farabale k'a sere o
E farabale k'a sere oloyin
E farabale k'a sere o
E farabale k'a sere oloyin o
E je k'a mu 'joko o
K'a mu 'joko o, k'a so 'tan
Itan t'o ma m'ogbon wa
O ye k'a lowo
K'a lowo, k'a lola
Ra moto repete
K'a ni'le lori
Sugbon k'a tun ni suuru
Suurulere o
Oooooo Eeeeeh hey!
O ni baba kan
Baba olowo olola
Baba motors, baba petroleum
MD/CEO ile-ise repete
Popular Jingo, philanthropist ni baba
O se f'onile, o tun se f'alejo
Oba orun eyi ni mo fe
Ki n lowo, ki n m'owo, ki n tun m'Olorun
Oh yes, k'oro mi le d'ayo o
K'oro mi le d'ayo o
Ah oh yee o, k'oro mi le d'ayo o
K'oro mi le d'ayo o
Ah oh yee o, k'oro mi le d'ayo o
Owo f'eju m'omo o
Owo f'eju m'omo o eeeeh
Owo f'eju m'omo baba o
Owo f'eju m'omo o
Owo f'eju m'omo o eeeeh
Owo f'eju m'omo o
Owo f'eju m'omo o aaaah
Ikun n j'ogede, ikun n re'di mole
Ikun o mo p'ohun to dun o (ko mo p'ohun to dun o)
Lo n pa'ni laye o
Ki lomo f'owo se o eeeeh? (Ooo eeeh)
Ki lomo f'owo se a eeeeh? (Aaa eeeh)
Pansaga paraga
E fun mi ni ti'bi
Onijekuje
Ikun o mo p'ohun to dun o (ko mo p'ohun to dun o)
Lo n pa'ni laye o
Baa o ba mo 'bi a mi re
Se b'aa mo bi a ti wa
Baa o ba mo 'bi a mi re
Se b'aa mo bi a ti wa
Omo eni i buru k'a fi f'ekun pa o
Baba gba mi o, mo ma yege
Mo ma yege (Iyeeee mo yege)
Iyeee iyeeee mo yege e (Iyeeee mo yege)
Baba gba mi o (Iba mi ma seun o)
Iba mi ma seun o (Iba mi ma seun o)
Iba iba iba mi ma seun o (Iba mi ma seun o)
Aye oniyo re o (maa yo o)
Ma yo, ma yo, ma yo, ma yo, ma yo (maa yo o)
Aye oniyo re o (maa yo o)
Ma yo, ma yo, ma yo, ma yo, ma yo (maa yo o)
Aye oniyo re o (maa yo o)



Авторы: Mike Abdul


Midnight Crew - IGWE
Альбом IGWE
дата релиза
07-04-2012




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.