Songtexte Aranbada - 9ice
                                                O'wu 
                                                f'akuko, 
                                                baba 
                                                mi
 
                                    
                                
                                                Aranbada 
                                                laye
 
                                    
                                
                                                Aranbada 
                                                laye
 
                                    
                                
                                                Akuko 
                                                baba 
                                                mi 
                                                kan 
                                                lai 
                                                lai
 
                                    
                                
                                                Owo 
                                                ni 
                                                    o 
                                                je, 
                                                koni 
                                                je 
                                                agbado, 
                                                oh-ohh
 
                                    
                                
                                                Akuko 
                                                baba 
                                                mi 
                                                kan 
                                                lai 
                                                lai
 
                                    
                                
                                                Owo 
                                                ni 
                                                    o 
                                                je, 
                                                koni 
                                                je 
                                                agbado, 
                                                oh-ohh
 
                                    
                                
                                                Aranbada 
                                                laye
 
                                    
                                
                                                Owo 
                                                nio 
                                                je 
                                                oh, 
                                                owo 
                                                ni 
                                                    o 
                                                je 
                                                oh, 
                                                oh-ohh
 
                                    
                                
                                                Ara 
                                                    n 
                                                ba 
                                                f'owo 
                                                da
 
                                    
                                
                                                Owo 
                                                nio 
                                                je 
                                                oh, 
                                                owo 
                                                ni 
                                                    o 
                                                je 
                                                oh
 
                                    
                                
                                                Money 
                                                na 
                                                the 
                                                root 
                                                of 
                                                all 
                                                evil
 
                                    
                                
                                                Ko 
                                                de 
                                                shey 
                                                ma 
                                                ni, 
                                                tori 
                                                owo 
                                                yi 
                                                dun
 
                                    
                                
                                                Kudiratulai, 
                                                obirin 
                                                lowo
 
                                    
                                
                                                Eyin 
                                                obirin, 
                                                    e 
                                                dakun, 
                                                shet'emi
 
                                    
                                
                                                Owo, 
                                                    a 
                                                pe 
                                                ka'nuko
 
                                    
                                
                                                Owo, 
                                                owo 
                                                ihoho
 
                                    
                                
                                                That 
                                                Gucci, 
                                                Prada 
                                                (owo 
                                                ni)
 
                                    
                                
                                                Holiday 
                                                for 
                                                Bahamas 
                                                (owo 
                                                ni)
 
                                    
                                
                                                Gb'omo 
                                                wa 
                                                ki 
                                                mi, 
                                                owo 
                                                lon 
                                                na 
                                                ni 
                                                (owo 
                                                lon 
                                                na 
                                                ni)
 
                                    
                                
                                                Akuko 
                                                baba 
                                                mi 
                                                kan 
                                                lai 
                                                lai
 
                                    
                                
                                                Owo 
                                                ni 
                                                    o 
                                                je, 
                                                koni 
                                                je 
                                                agbado, 
                                                oh-ohh
 
                                    
                                
                                                Akuko 
                                                baba 
                                                mi 
                                                kan 
                                                lai 
                                                lai
 
                                    
                                
                                                Owo 
                                                ni 
                                                    o 
                                                je, 
                                                koni 
                                                je 
                                                agbado, 
                                                oh-ohh
 
                                    
                                
                                                Aranbada 
                                                laye
 
                                    
                                
                                                Owo 
                                                nio 
                                                je 
                                                oh, 
                                                owo 
                                                ni 
                                                    o 
                                                je 
                                                oh-ohh
 
                                    
                                
                                                Imagine 
                                                say 
                                                na 
                                                me 
                                                get 
                                                money 
                                                pass
 
                                    
                                
                                                    I 
                                                go 
                                                pay 
                                                all 
                                                lectures 
                                                fees 
                                                and 
                                                put 
                                                an 
                                                end 
                                                to 
                                                ASUU 
                                                strike
 
                                    
                                
                                                Imagine 
                                                say 
                                                    I 
                                                be 
                                                babalawo
 
                                    
                                
                                                    I 
                                                go 
                                                fight 
                                                spiritual 
                                                for 
                                                Corona, 
                                                make 
                                                my 
                                                people 
                                                dey 
                                                alright
 
                                    
                                
                                                T'enu 
                                                ba 
                                                je, 
                                                oju 
                                                    a 
                                                ti
 
                                    
                                
                                                Ohun 
                                                t'owo 
                                                ba 
                                                sheti, 
                                                ile 
                                                lo 
                                                ma 
                                                gbe
 
                                    
                                
                                                Eni 
                                                ba 
                                                gbin 
                                                gedu 
                                                s'ojude 
                                                mi
 
                                    
                                
                                                Adigun, 
                                                    o 
                                                fe 
                                                funmi 
                                                ni 
                                                iboji 
                                                ni
 
                                    
                                
                                                Akuko 
                                                baba 
                                                mi 
                                                kan 
                                                lai 
                                                lai
 
                                    
                                
                                                Owo 
                                                ni 
                                                    o 
                                                je, 
                                                koni 
                                                je 
                                                agbado, 
                                                oh-ohh
 
                                    
                                
                                                Akuko 
                                                baba 
                                                mi 
                                                kan 
                                                lai 
                                                lai
 
                                    
                                
                                                Owo 
                                                ni 
                                                    o 
                                                je, 
                                                koni 
                                                je 
                                                agbado, 
                                                oh-ohh
 
                                    
                                
                                                Aranbada 
                                                laye
 
                                    
                                
                                                Owo 
                                                nio 
                                                je 
                                                oh, 
                                                owo 
                                                ni 
                                                    o 
                                                je 
                                                oh, 
                                                oh-ohh
 
                                    
                                
                                                Lekan 
                                                oh 
                                                Akinyele 
                                                (Akinyele)
 
                                    
                                
                                                Lekan, 
                                                oloore 
                                                mi 
                                                ni
 
                                    
                                
                                                Lekan 
                                                oh 
                                                Akinyele 
                                                (Akinyele)
 
                                    
                                
                                                Lekan, 
                                                oloore 
                                                mi 
                                                ni
 
                                    
                                
                                                Egbon 
                                                Femi 
                                                Oko 
                                                L'ere 
                                                Agbe, 
                                                gbogbo 
                                                Akure
 
                                    
                                
                                                Loko', 
                                                iwo 
                                                l'egbon 
                                                Femi 
                                                Oko 
                                                L'ere 
                                                Agbe, 
                                                Akure 
                                                ni
 
                                    
                                
                                                Gentle, 
                                                alashe 
                                                G-Unit
 
                                    
                                
                                                Gentle, 
                                                egbon 
                                                Lekan 
                                                Akinyele
 
                                    
                                
                                                Gentle, 
                                                oko 
                                                Abidemi
 
                                    
                                
                                                Gentle, 
                                                gbogbo 
                                                efon 
                                                alaye
 
                                    
                                
                                                Lekan 
                                                Akinyele, 
                                                imule 
                                                wo'le 
                                                kanle
 
                                    
                                
                                                Lekan 
                                                Akinyele, 
                                                imule 
                                                wo'le 
                                                kanle
 
                                    
                                
                                                Wo'le 
                                                kanle, 
                                                wo'le 
                                                kanle
 
                                    
                                
                                                Iwo 
                                                loni 
                                                ile, 
                                                wo'le 
                                                kanle
 
                                    
                                
                                                Eru 
                                                    o 
                                                b'omo 
                                                oloode, 
                                                wo'le 
                                                kanle
 
                                    
                                
                                                Eru 
                                                    o 
                                                gbudo 
                                                b'omo 
                                                Ogbomojugun, 
                                                wo'le 
                                                kanle-e
 
                                    
                                
                                                (Olumix 
                                                on 
                                                the 
                                                Mix)
 
                                    
                                 
                            Attention! Feel free to leave feedback.
                 
                                                         
                                                         
                                                        