Brymo - Adédọ̀tun Songtexte

Songtexte Adédọ̀tun - Brymo




Awon adan fo loke
Won foka soju orun
Won oma mobi wonlo
Eledua lonsekewon
Kokeyin si e ore o
Ohun o nwa,o wa niwaju re ooo
A--de--dotun! Oyindamola mi
Ero gbogbo ebangbere adedotun o
Awon adan fo loke
Nigbaigba wonkoju orun
Won n oma mohun wonje
Eledua lonsho won lonbowon
Kopamo si e ore ooooo
Ohunwalosokoto owa lapo sokoto
Adedotun! Oyindamola mi
Ero gbogbo eban gbere,Adedotun o
Adedotun oyindamolami
Ero gbogbo eban gberin Adedotun o
Kopamo si e ore ooo
Ohun onwa o wa niwaju re ooooo.



Autor(en): Olawale Olofo'ro



Attention! Feel free to leave feedback.