Brymo - Olúmọ Songtexte

Songtexte Olúmọ - Brymo




Mo nlo sake mofe lorojogbon o
Mo nlo sabeokuta mofe Lori
Omo Soyinka...
Osoyinka
Osoyinka oooo
Instrumental ...
Be lo sowu,be baremu oooo
Be ba ri baba iyabo,e ba mi ki
Ebora owuuu
Ebora owu o oo
Ebora owuuuuu eeee
Ebora owu o ooo
Instrumental...
Be lo sabe okuta,ilu olumo
Be ba ra alake,e bami ki



Autor(en): Olawale Olofo'ro


Brymo - Oṣó
Album Oṣó
Veröffentlichungsdatum
27-03-2018




Attention! Feel free to leave feedback.