El Mahboobu Fillah - Baba lamerica (feat. Al Ikhlãsiy SFK) Songtexte

Songtexte Baba lamerica (feat. Al Ikhlãsiy SFK) - El Mahboobu Fillah




Oti pada wa koja ilu re
Markaz tan ti gbe fo border
Adamo ti n gbe lamerica
Adamo ti n gbe lamerica
Oti pada wa koja ilu re
Markaz tan ti gbe fo border
Adamo ti n gbe lamerica
Adamo ti n gbe lamerica
Oti pada wa koja ilu re
Markaz tan ti gbe fo border
Adamo ti n gbe lamerica
Ti n gbe lamerica
Oti pada wa koja ilu re
Markaz tan ti gbe fo border
Adamo ti n gbe lamerica
Adamo ti n gbe lamerica
Se lero pe mo tun le ma gbon
Bi won ni n wa yin sheikh adam
Je n ja e tan Alhaji khalid
Nijo ti mo fe finu iya le
Ti n tikole orun bo wa saye
Ni mo tin pariwo sheikhu adam
Mi o ke nijo tiwon so mi le
Adamo ni mo tun pariwo
Bere lowo daddy mi nilorin
Iwa eto ni pe ka pon baba wa
Kosa sodun nibi madahi won
Sawon ko ni won so mimo do be
Sawon ko ni won so mimo do be
Sawon ko ni won soro baba yin
Sibi tira ki aye le ma kaa
Sawon ko ni video waasi won
Si tun gba likes ni facebook
Se rodo ko wonu ilu wa
Won ti pale mo pelu imo won
Na se wa baba sinu ilu wa
Adamo tin gbe lamerica
Adamo tin gbe lamerica
Oya lo ba mudeeru fun address yen
Adamo tin gbe lamerica
حيُّو مَعِى آدَمَا
حيُّو مَعِى آدَمَا
زَعِيْمَنَا الْمُكْرَمَا
وقَـدِّرُوا دَائِـمـا
مَجْهُودَهُ الْأَعْظَمَا
مَسِيْرُهُ قَدْ كَفَى
مَسِيْرُهُ قَدْ كَفَى
عَطِيّةً تُعْتَفِى
فَفِى يَدِيْهِ الرِّفَا
لمَنْ هَمَى وَاعْتَفَى
لمَنْ هَمَى وَاعْتَفَى
Oti pada wa koja ilu re
Markaz tan ti gbe fo border
Adamo ti n gbe lamerica
Adamo ti n gbe lamerica
El mahbooooob
فَإنَّـهُ مُصْطَفَى
وَمَنْبَعٌ لِلصَّفَا
وَمِشْعَلٌ فِى الْوَفَا
ومَصْدَرٌ للشِّفَا
ذُرَى الْمَعَالِى عَلَا
بالْعِلْمِ ثم اعتلى
مقَامَ أَهْلِ الْعُلَا
وَفَازَ بَيْنَ المَلا
Eyin kule le tin soro re
Ita ni won ti n woran e
Adamo to wonu omi
Lori odan e o pade re
Se ko ko e lori ko so
Awa n sope baba wa
Nigbogbo aye ko si ru e
Biro ba ni ja iro wa
Daruko re ja ka mo lu re
Olohun lo se haji adam
Ni idunnu aye awa kan
Idamu lo je fun ota re
Emi n fe sheikhu Adam
Baba to so mimo doyin
Oti pada wa koja ilu re
Markaz tan ti gbe fo border
Adamo ti n gbe lamerica
Ti n gbe lamerica
Oti pada wa koja ilu re
Markaz tan ti gbe fo border
Adamo ti n gbe lamerica
Adamo ti n gbe lamerica
Oti pada wa koja ilu re
Markaz tan ti gbe fo border
Adamo ti n gbe lamerica
Adamo ti n gbe lamerica



Autor(en): Abdulazeez Saheed Olalekan



Attention! Feel free to leave feedback.