Fela Kuti - Lover Songtexte

Songtexte Lover - Fela Kuti




Ololufe mi, ti e ni mo fe
Alayanfe mi, ti e ni mo fe
Ololufe mi, mi o se tiwon mo
Alayanfe mi, ti e ni mo fe
Wa f'enu ko mi l'enu, oh-oh
Wa f'ara ro mi l'ara o
Eh, eh, eh, eh, eh, eh
Alayanfe mi, ti e ni mo fe
Ololufe mi, ti e ni mo fe
Alayanfe mi, mi o se tiwon mo
Alayanfe mi, ti e ni mo fe
Wa f'enu ko mi l'enu
Wa f'ara ro mi l'ara o
Oh, oh, oh, oh, oh



Autor(en): Fela Anikulapo Kuti



Attention! Feel free to leave feedback.