Songtexte Talebale - JayMikee
A
jẹ'
bí
ọmọdé
tí
ìyá
rẹ
rán
lọ
s'ọjà
Ah
ah
ah
ah
ah
ah
Ọjà
ilé
ayé
láti
ra
láti
tá
Ah
ah
ah
ah
ah
ah
Ṣùgbọ'n
tí
ilẹ'
bá
bẹ'rẹ'
si
ní
ń
ṣú
Tí
òkùnkùn
bá
bo
'lẹ'
Ti
oníkálukú
bá
pá
lẹ
ọjà
mọ
Ma
jẹ'
kí
ń
gbàgbé
láti
kọ
'ri
si
'lè
Jésù
ó
jọ'wọ'
ó
má
má
jẹ'
ń
kùnà
Kíi
má
bá
ṣ'
ègbé
ló
ṣe
kú
fún
mi
Jésù
ó
jọ'wọ'
ó
má
má
jẹ'
n
ṣìnà
Kíi
má
bá
ṣ'
ègbé
ló
ṣe
kú
fún
mi
Nígbà
t'álẹ'
bá
lẹ'
T'ọjà
ayé
tú
Jẹ'
kí
n
r'
ọkọ
rẹ
bá
relé
Nígbà
t'álẹ'
bá
lẹ'
T'ọjà
ayé
tú
Jẹ'
kí
n
r'
ọkọ
rẹ
bá
relé
Ìjọba
ọrùn
dá
bí
àwọn
wúńdíá
mẹ'wàá
Ah
ah
ah
ah
ah
ah
ah
Tí
wọn
mú
fìtílà
wọn
lọ
pàdé
ọkọ
ìyàwó
Ah
ah
ah
ah
ah
ah
ah
Elédùmarè
má
má
jẹ'
kí
n
dí
alaigbagbọn
Fún
mi
ní
ọgbọ'n
bí
àwọn
wúńdíá
ọlọ'gbọ'n
Kólóbó
mì
rèé
ó
Rọ'
kún
pẹ'lú
òróró
rẹ
Kíi
n
fí
dúró
dé
ọ'
Jésù
ó
jọ'wọ'
ó
má
má
jẹ'
ń
kùnà
Kíi
má
bá
ṣ'
ègbé
ló
ṣe
kú
fún
mi
Jésù
ó
jọ'wọ'
ó
má
má
jẹ'
n
ṣìnà
Kíi
má
bá
ṣ'
ègbé
ló
ṣe
kú
fún
mi
Nígbà
t'álẹ'
bá
lẹ'
T'ọjà
ayé
tú
Jẹ'
kí
n
r'
ọkọ
rẹ
bá
relé
Nígbà
t'álẹ'
bá
lẹ'
T'ọjà
ayé
tú
Jẹ'
kí
n
r'
ọkọ
rẹ
bá
relé
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
(Bá
relé)
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
(Bá
relé)
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
(Bá
relé)
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
(Bá
relé)
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
(Bá
relé)
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
(Bá
relé)
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
(Bá
relé)
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
(Bá
relé)
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
(Bá
relé)
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
(Bá
relé)
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
(Bá
relé)
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
(Bá
relé)
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
Mú
Mí
délé
ó
ó
Mú
mi
délé
Jésù
ó
jọ'wọ'
ó
má
má
jẹ'
ń
kùnà
Kíi
má
bá
ṣ'
ègbé
ló
ṣe
kú
fún
mi
Bàbá
jọ'wọ'
ó
má
má
jẹ'
n
ṣìnà
Kíi
má
bá
ṣ'
ègbé
ló
ṣe
kú
fún
mi
Nígbà
t'álẹ'
bá
lẹ'
T'ọjà
ayé
tú
Jẹ'
kí
n
r'
ọkọ
rẹ
bá
relé
Nígbà
t'álẹ'
bá
lẹ'
T'ọjà
ayé
tú
Jẹ'
kí
n
r'
ọkọ
rẹ
bá
relé
Baba
Ah!
Attention! Feel free to leave feedback.