Rybeena - Go Harder Songtexte

Songtexte Go Harder - Rybeena




(Bobo Rybeena yẹn sẹh)
(Rybeena lonpè ni abi Sabina?)
(Nlike rárá, kotiẹ fine, ẹnu tunwá gun)
(Ẹshá l'ọdun mèji t'ẹlo, kẹ ko'gbá n'lè)
(Tori gbogbo yin, ẹn ṣh'olorin)
(It's Jay Fred, The Beat Wizard)
Ayy-ah
Itákun, itákun toni k'èmi goke
Iyana ohun gbèmi dèbẹ, jábọ
Itákun, itákun toni k'èmi goke
Iyana ohun tèrè mi, wọn l'oni jábọ, oh-ah
We go harder, bad man can't give up
Only mama no love me with condition
Tinbá ranti ngbá n'lowo, o mán kámi n'ṣhàn, uh-uh
So, no time, èbi o mi mọ
Tinbá ti ri maga t'omá l'ari mọ, 'ṣhèè ninu mi dun bi k'áṣá ti ri kàn, uh (gbè wa, gbè wa)
Dákun, k'ámá ṣhèè l'ásàn, oje mi ti jẹyá wọn
Olori o jọ wọn, biti filá kọ
Okay, mofi cana pẹlu Backii wèrá wọn, ko ṣháti jọrá wọn
Tinbá ti mu'gbo mi, moti igbágbọ
Yè, èmi Obama
David in the midst of Goliath
Adewale, ṣh'omọ o para
Bomb everywhere like Osama
O l'árá, para-para
Èyàn mi ni Shehu Bulala
Stealing every show like kidnapper
You dey find money, oun data, gbà sapa
Ayy, I dey follow you dey bomb, you carry money, you run
Shey because I still dey scut for your place, you come dey use matter dey puff?
Ọdọ mummy mi mo lọ, ngbá tóh wá, tiko sibi t'ámá lọ
Sugbọn ọrọ kàn ni mo básọ, mo sọh fun "you go meet me for the top" (mtcheew)
We go harder, bad man can't give up
Only mama no love me with condition
Tinbá ranti ngbá n'lowo, o mán kámi n'ṣhàn, uh-uh
So, no time, èbi o mi mọ
Tinbá ti ri maga t'omá l'ari mọ, 'ṣhèè ninu mi dun bi k'áṣá ti ri kàn, uh (gbè wa, gbè wa)
Dákun, k'ámá ṣhèè l'ásàn, oje mi ti jẹyá wọn
Olori o jọ wọn, biti filá kọ
Okay, mofi cana pẹlu Backii wèrá wọn, ko ṣháti jọrá wọn
Tinbá ti mu'gbo mi, moti igbágbọ
Yè, èmi Obama
David in the midst of Goliath
Adewale, ṣh'omọ o para
Bomb everywhere like Osama
O l'árá, para-para
Èyàn mi ni Shehu Bulala
Stealing every show like kidnapper
You dey find money, oun data, gbà sapa
Dákun, k'ámá ṣhèè l'ásàn, oje mi ti jẹyá wọn
Olori o jọ wọn, biti filá kọ
Yè, mofi cana pẹlu Backii wèrá wọn, ko ṣháti jọrá wọn
Tinbá ti mu'gbo mi, moti igbágbọ



Autor(en): Atanda Adewale


Attention! Feel free to leave feedback.