9ice feat. Asa - Pete Pete (feat. Asa) Lyrics

Lyrics Pete Pete (feat. Asa) - Asa , 9ice



Ojo re bi ana ta gb'ominira,
1960 N'igba yen tis easy gege bo se wi
Ta rugbo, t'omidan lon dunu pa ti d'ominira
Ominira indeed abi, ewo naira wa
Ilu polukurumusu
T'ewe t'agba lon j'eyan won nisu
Abe ori, ewe eri, sugbon e ofewi
Abe ori, agba eri atenuje lofe p'ayin
Petepete t'ana ni popa
Eni bataba, kolo mofe ni
Sebe l'ema sun
Teba sope 'omo nkankan
Eyin aro lema waa (sebe la ma)
Mewa n'sele o
Sebe l'ema sun (sebe lema sun)
Bi eni wo'seju akan o
Eyin aro lema wa a (mewa nsele o)
Kini suuru ti o l'ere?
Kini seti ko s'ere?
Won sa l'eyan ti o l'oruko
Okuku sise, ode'n rere e
Ah! ede s'ope a siwa l'omode
Nkan sa l'eye je k'agbado t'ode
9ice oro gidi l'oso
Oro to o ni'lari l'oso
An'lati fi laka yesi
K'asoro sibi t'orowa
Boda siko 'bo yen
Won a wa s'adugbo
Won a'somo jeje
Eje kan wole tan gbogbo eje tan je da w'oke ise
Toba tun se were, la siko ibo
Won ani k'odo tolo bere
Won a senu mere, kalokalo gbe nkan mi senu wuye
Afira aditu ti iwole, talo dibo fun?
Pasan ta fi na 'yale
Onbe lori aja fun.
Odo elo tunramu, ema je an'pagbon ni funfun
Fun yin, mowi temi
Asegbe kan kosi o
Asepamo lowa
Ase sile labo waba
Emi oti ku,
Mo s'ile s'ise
Mo sile f'owo r'ewo
Mo sile tule mise
Sebe l'ema sun
Teba sope 'omo nkankan
Eyin aro lema waa (sebe la ma)
Mewa n'sele o
Sebe l'ema sun (sebe lema sun)
Bi eni wo'seju akan o
Eyin aro lema wa a (mewa nsele o)
Asa ose omo nla



Writer(s): 9ice


9ice feat. Asa - Tradition
Album Tradition
date of release
30-12-2015



Attention! Feel free to leave feedback.