9ice - Gbogbo Were Lyrics

Lyrics Gbogbo Were - 9ice



Aye mo
Orí ayé
(Chrs)
Ayé mo
mi ò lowo lọ′wọ'
Ayé mo ń bẹ gbé pe
Ayé mo ń mole
Kàkà ki n wa yẹ rare
gbogbo wéré bo
gbogbo wéré bo
Gunugu mi ò we
gbogbo wéré bo oo
gbogbo wéré bo oo
(Stanza 1)
Wọn na náírà
Mo ń náà dollar
Wọn mo ṣe sọ
Wọn lọ Russia
Mo lọ Canada
bo loti rowo
Ota ó mọ pe owo ni koko
Owó di dandan
Báwo ṣe se
Kan bi mi
Kan b′Olorun lejo
Itakun to so gba
Lọ sọ elegede
Èmi ti mo na
Náà ni mo tun silẹ
Anywhere money dey
I go dey
Anywhere blessing dey
I go dey
Life without money
I no dey. I nodey. I no dey eeeh...
(Chrs)
Ayé mo
mi ò lowo lọ'wọ'
Ayé mo ń bẹ gbé pe
Ayé mo ń mole
Kàkà ki n wa yẹ rare
gbogbo wéré bo
gbogbo wéré bo
Gunugu mi ò we
gbogbo wéré bo o
Ma ti gbogbo wéré bo oo
(Stanza 2)
Ta ń jẹun
ajá ń ju irú gan naa
Gangan naa
If money dey
Friends go come, family go talk dem belong
If money no dey
Ìwọ ni kan ran
Ṣe p ′owó di dandan
Olúwa wa tán ọ′ràn naa
Leyin owó. Owo ni
Leyin owó. Owo ni
Owó fi ń kólé
Owo ni a fi ń yẹ
Owó fi ń Segun ota
Owó ni a fi ń gbé ota
Owo la fi ń ṣe ọkọ obìnrin
Owó óò... Ìwọ ro oooo
(Chrs)
Ayé mo
mi ò lowo lọ'wọ′
Ayé mo ń bẹ gbé pe
Ayé mo ń mole
Kàkà ki n wa yẹ rare
gbogbo wéré bo
gbogbo wéré bo
Gunugu mi ò we
gbogbo wéré bo o
Ma ti gbogbo wéré bo oo



Writer(s): Rr


9ice - G.O.A.T
Album G.O.A.T
date of release
30-03-2018




Attention! Feel free to leave feedback.