Lyrics Jesu Joy - Artist Unknown
Moyin
Jesu
logo
Moyin
Jesu
logo
Ipe
to
pe
mi,
ipe
ola
ni
Moyi
Jesu
logo
Moyin
Jesu
logo
Moyin
Jesu
logo
Ipe
to
pe
mi,
ipe
ola
ni
Moyin
Jesu
logo
Mo
ti
ni
Jesu
lore
O
j'ohun
gbogbo
fun
mi
Oun
nikan
larewa
ti
okan
mi
fe
Oun
nitanna
ipado
Oun
ni
Enikan
naa
To
le
we
mi
nu
kuro
nin'ese
mi
Olutunu
mi
lo
je
ni
gbogbo
wahala
Oun
ni
ki
n
kaniyan
mi
l'Oun
lori
Oun
n'Itanna
Ipado
Irawo
Owuro
Oun
nikan
l'Arewa
ti
okan
mi
fe
Moyin
Jesu
logo
Moyin
Jesu
logo
Ipe
to
pe
mi,
ipe
ola
ni
Moyin
Jesu
logo
Moyin
Jesu
logo
Moyin
Jesu
logo
Ipe
to
pe
mi,
ipe
ola
ni
Moyin
Jesu
logo
Instrumental!!!
O
gbe
gbogbo
banuje
At'irora
mi
ru
O
j'Odi
agbara
mi
n'gba
danwo
Tori
Re
mo
k'ohun
gbogbo
Ti
mo
ti
fe
sile
O
si
f'agbara
Re
gbe
okan
mi
ro
Bi
aye
tile
ko
mi
Ti
Satan'
dan
mi
wo
Jesu
yoo
mu
mi
d'opin
irin
mi
Oun
n'Itanna
ipado
Irawo
Owuro
Oun
nikan
l'Arewa
ti
okan
mi
fe
Moyin
Jesus
logo
Moyin
Jesu
logo
Ipe
to
pe
mi,
ipe
ola
ni
Moyin
Jesu
logo
Moyin
Jesu
logo
Moyin
Jesu
logo
Ipe
to
pe
mi,
ipe
ola
ni
Moyin
Jesu
logo
Oun
ki
yo
fi
mi
sile
Be
ki
yo
ko
mi
nihin
Niwon
ti
m'ba
figbagbo
pofin
Re
mo
O
jodi
ina
yi
mi
ka
N
k'y'o
beru-keru
Y'o
fi
manna
Re
bokan
mi
t'ebi
npa
Gba
m'ba
dade
n'ikehin
N
o
roju
'bukun
Re
Ti
adun
Re
y'o
ma
san
titi
lai
Oun
n'Itanna
ipado
Irawo
Owuro
Oun
nikan
l'Arewa
ti
okan
mi
fe
Moyin
Jesu
logo
Moyin
Jesu
logo
Ipe
to
pe
mi,
ipe
ola
ni
Moyin
Jesu
logo
Moyin
Jesu
logo
Moyin
Jesu
logo
Ipe
to
pe
mi,
ipe
ola
ni
Moyin
Jesu
logo
Moyin
Jesu
logo
Moyin
Jesu
logo
Ipe
to
pe
mi,
ipe
ola
ni
Moyin
Jesu
logo
Attention! Feel free to leave feedback.