Brymo - Bá’núsọ Lyrics

Lyrics Bá’núsọ - Brymo



Abéré á lo
Abéré á lo
K'ó okùn ó ò
A ò won
A ò won
Ení a máà de ò
Bá'núso
Bá'núso
b'enìyan
Bá'núso
Bá'núso
b'enìyan
Omijé á gbe
Omijé á gbe
Ìbànújé á dèrin ò
Eniafé
Eniafé lamò o
A ò mo'ni ni ò
Bá'núso
Bá'núso
b'enìyan
Bá'núso
Bá'núso
b'enìyan
Ení ma b'ésù jeun
Síbíi á gùn gan
Eni ò áù
Ówá jeé
Òsèlú layé ò
Bá'núso
Bá'núso
b'enìyan
Bá'núso
Bá'núso
b'enìyan
Èyin ará
Ewá gbó òò
Òrò kan se ùrùn ùrùn nínú iii
kín
Kín
bá'núso
Bá'núso
N'òní b'enìyan
Bá'núso
Bá'núso
b'enìyan
Bá'núso
Bá'núso
b'enìyan



Writer(s): Olawale Olofo'ro


Brymo - Oṣó
Album Oṣó
date of release
27-03-2018




Attention! Feel free to leave feedback.