Brymo - Ọ̀run n Móoru Lyrics

Lyrics Ọ̀run n Móoru - Brymo



Te ti kogbo
Ile oba ti gbana
Awon ijoye
Won ni kosowo lowo oba
Won n soro re leyin
Olori loun rofo loba n sanra
Orun n moruuuu
Orun n moruuuu
Eni lo lomo
Eni bo lomo
Oba o ye
Ko pa ri
Ko binu
Oni ki won pade oun laafin
Awon ijoye
Won tiju
Won wa ro oba won soro re leyin
Olori lo n roka
Loba n sanra
Orun n mooru
Orun n mooru
Eni lo lomo
Eni bo lomo
Orun n mooru
Orun n mooru
Eni lo lomo
Eni bo lomo



Writer(s): Olawale Olofo'ro


Brymo - Yellow
Album Yellow
date of release
01-04-2020




Attention! Feel free to leave feedback.