C Blvck - Omo Aunty Mi Lyrics

Lyrics Omo Aunty Mi - C Blvck



Ouuhhh
C blvck waddiddoo
Lyrical Mafia
Ẹyin tẹ ti sun lati ọwọ alẹ
shiwọ f'alarọ
Haji m'ohun... haji mọ voice
Haji lo gbe microphone wọ church (Ouuhhh)
Ọmọ aunty mhi oo keere ninu aye (Ajeh)
Ko easy k'ọmọ a jẹ pako rale (Oje)
Oo fẹ ṣiṣẹ o fẹ jaye, oju a bo bi ẹniti o jo'na mọ'le (Ajeh)
Ọmọ aunty mhi oo keere ninu aye (Ajeh)
Ko easy k'ọmọ a jẹ pako rale (Oje)
Oo fẹ ṣiṣẹ o fẹ jaye, oju a bo bi ẹniti o jo'na mọ'le(Ajeh)
(Ouuhhh) Oh pọ ko dun, oh leke nka
Oh dun ko pọ, wọn f'oje ka
Aya koto, aya kata
Wa pakara ye taraka
Oh pọ ko dun, oh leke nka
Oh dun ko pọ, wọn f'oje ka
Aya koto, aya kata
Wa pakara ye taraka
Oluwa gbemi ga kon she bii ti ladder
Tọn ba nhi ki lon nda k'on she bii ti wákà
Oh maa le k'ẹlẹsẹ toh leh b'alapa ja
Oun gan o nhi fẹẹ gba kanar wọ Canada
On gba lori mhi o da nga já,o da,o da, o da nga ja
Bami w'ọmọ pupa to bah ja fah fah,to ba ja, to ba ja,to ba ja fah fah
Bo'jẹ dudu ab'o ja akata, ab'o akata, ab'o pata
Ologo rainbow wọn lo ja s'ọla,o ja s'owo, o tun ja s'ọla
kọ kọkọ ri kọkọ
bọ bọbọ ri bọbọ
jọ jọjọ ri jọjọ
Dọdọ yọ wọ'le, gọ gọ ri gọ gọ(Ouuhhh)
Ọmọ aunty mhi oo keere ninu aye (Ajeh)
(Gbe gbe gbe gbe gbe)
Ko easy k'ọmọ a jẹ pako rale (Oje)
(Kere gbe gbe gbe)
Oo fẹ ṣiṣẹ o fẹ jaye, oju a bo bi ẹniti o jo'na mọ'le (Ajeh)
(Gbe tan gbe tan)
Ọmọ aunty mhi oo keere ninu aye (Ajeh)
(Gbe gbe gbe gbe gbe)
Ko easy k'ọmọ a jẹ pako rale(Oje)
(Kere gbe gbe gbe)
Oo fẹ ṣiṣẹ o fẹ j'aye, oju a bo bi ẹniti o jo'na mọ'le (Ajeh)
(Gbe tan gbe tan)
Oh pọ ko dun, oh leke nka
Oh dun ko pọ, wọn f'oje ka
Aya koto, aya kata
Wa pakara ye taraka
Oh pọ ko dun, oh leke nka
Oh dun ko pọ, wọn f'oje ka
Aya koto, aya kata
Wa pakara ye taraka
máa win, oh gara ku
Tẹ ba r'ewe, k'ẹ fah kanaku
Moti gbera k'ọta toh laju
Ẹyin Oluwa l'ogo, kẹ s'asalatu
Kọrọ to ya sọn ju titi to tẹh lọ
Wobi ma wo ibẹ ko mọ bi to fẹẹ lọ
fun wa nti wa, kẹ yọ oun tẹ fẹẹ yọ
Ai jẹbẹ ti wọ gau ẹti k'ẹran
O leh kuru oo keere,o kan leh tiirin oo benbe,mo le ku mhi o shere
Toh ba ti d'ọrọ kudi mhi o m'ere
Bọ' bi o waa jo oh eh ke-le
Heeehhh oju eh le me-le
O gbe yah, o gbe yeh
Filẹ f'awọn temi lori keke be
(Ouuhhh)
Ọmọ aunty mhi oo keere ninu aye (Ajeh)
Ko easy k'ọmọ a jẹ pako rale (Oje)
Oo fẹ ṣiṣẹ o fẹ jaye, oju a bo bi ẹniti o jo'na mọ'le (Ajeh)
Ọmọ aunty mhi oo keere ninu aye (Ajeh)
Ko easy k'ọmọ a jẹ pako rale (Oje)
Oo fẹ ṣiṣẹ o fẹ jaye, oju a bo bi ẹniti o jo'na mọ'le(Ajeh)
Oh pọ ko dun, oh leke nka
Oh dun ko pọ, wọn f'oje ka
Aya koto, aya kata
Wa pakara ye taraka
Oh pọ ko dun, oh leke nka
Oh dun ko pọ, wọn f'oje ka
Aya koto, aya kata
Wa pakara ye taraka
Ouuhhh
Ọmọ aunty mhi oo keere
Oo benbe
Ọmọ aunty mhi nhi general Mafia
Emi nhi Lyrical Mafia
End



Writer(s): C Blvck


C Blvck - Omo Aunty Mi - Single
Album Omo Aunty Mi - Single
date of release
30-10-2020




Attention! Feel free to leave feedback.