EmmaOMG - E Ti Tobi to Jesu (feat. Pelumi Deborah) Lyrics

Lyrics E Ti Tobi to Jesu (feat. Pelumi Deborah) - EmmaOMG



Oluwa tobi ni sioni
O si joba lori gbogbo orile ede
Je ki won yin oruko re ti o tobi
Ti osi leru, oh my God
Gbogbo aye n wariri
Ni oruko re, won nkorin
(Eti tobi to oo, Jesu)
Awon orun n seleri
Won foribale niwaju ite re o
Won so wipe (eti tobi to oo, Jesu)
Won ni Eti tobi to o, oh oh oh oluwa
(Eti tobi to oo, Jesu)
Won ni eti tobi to o, oh oh oh oh oluwa wa o
(Eti tobi to oo, Jesu)
Awon oke nla nla won foribale o
Tori iwo ni ogo ati ola ju oke nla ikogun won ni lo o
(Eti tobi to o, Jesu)
Iwo ti olorun ji dide kuro ninu oku
Lati gba wa kuro ninu ibinu ti n bo o
(Eti tobi to o, Jesu)
Iwo oluwa olorun to n gbe larin awon kerubu
To po ni ipa ati agbara o
(Eti tobi to o, Jesu)
Ani gbogbo aye n wariri
Ni oruko re won nkorin, yeee
(Eti tobi to o, Jesu)
Awon orun n seleri
Won foribale niwaju ite re
(Eti tobi to o, Jesu)
Won ni Eti tobi to o
Oh oh oh oh oluwa wa o
(Eti tobi to o, Jesu)
Ipekun ola, Ipekun iye ye eh eh eh
Eti tobi to oh oh oh oh
(Eti tobi oo, Jesu)
Ireti wa o, eri wa o oh oh oh eti tobi to oh oh oh
(Eti tobi to ooo, Jesu)
Itan sho to wole ro ro ro ro ro
Eti tobi to aye ati orun n bo oo won n juba
(Eti tobi to o Jesuuu), won foribale
Jordani ri o o pada seyin, okun ri o o sa
Eti tobi to olodumare
(Eti tobi to o, Jesu)
Abetilukarabiajere baba mi agba oye
Eti tobi to oh oh oh oh oh
(Eti tobi oo, Jesu)
Tori na gbogbo aye n wariri ni
Oruko re won nkorin
(Eti tobi to o, Jesu)
Awon orun n seleri
Won foribale niwaju ite re eh eh eh
(Eti tobi to o, Jesu)
Won ni eti tobi to oo oh oh oh oluwa wa
(Eti tobi to oo, Jesu)
Gbogbo idile Jesse
Jesu won nkorin foribale, won so wipe
(Eti tobi to o, Jesu)
Ipekun Ola, Ipekun oro
Ipekun agbara oh, eti tobi to
Eti tobi to oh oh oh oh oh
(Eti tobi to o, Jesu)
Ore ati ola nla ni o wa ni iwaju re
Ipa ati ewa nbe nibi mimo re
(Eti tobi to o, Jesu)
Aiikakatan o, aiibubutan o
Atobi loye, ongbe leyin eni a n da loro oo
Eti Eti Eti tobi to o
(Eti tobi to o, Jesuuuuu)
Jesu gbogbo aye n wariri
Ni oruko re won nkorin
(Eti tobi to oo, Jesu)
Awon orun n seleri
Won foribale niwaju ite re ohhhh eh
(Eti tobi to oo, Jesu)
Won juba fun ajunilo o
E ba n juba f'ajunilo eh
E ba n seba f'ajunilo o
E ba gbo'suba f'ajunilo
E ba n gbo osuba f'ajunilo o
E ba n kira f'ajunilo o
E ba n juba f'ajunilo o
E bami juba f'ajunilo
E ba n gbo'suba f'ajunilo o
E ba n seba f'ajunilo o
E ba mi juba f'ajunilo o
E ba n juba f'ajunilo o
Ani gbogbo aye n wariri
Ni oruko re won nkorin
"Eti tobi to o Jesu"
Oh My God



Writer(s): Emmanuel Edunjobi


EmmaOMG - E Ti Tobi to Jesu
Album E Ti Tobi to Jesu
date of release
09-04-2024




Attention! Feel free to leave feedback.