Fela Kuti - Fight To Finish Lyrics

Lyrics Fight To Finish - Fela Kuti



Ẹba mi wa (eh oh)
Ẹba mi wa wa o ehn
Bo s'ake ni (eh oh)
Ẹba mi wa wa o (ehn)
Bo s'ebọn ni (ehn oh)
Ẹba mi wa wa o (ehn ehn)
Ẹgbe ke yan
Ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa wa o (ehn eh o)
Arinfin to gbe ko mi ti pọju
Iwosi to gbe kan mi ti pọju
Irẹjẹ to gbe wọ mi ti pọju
Iwosi to gbe kan mi ti pọju
Bo s'ake ni
Ẹba mi wa wa o (ehn eh o)
Ẹba mi wa (eh oh)
Ẹba mi wa wa o (eh)
Bo s'ake ni (eh oh)
Ẹba mi wa wa o
Ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa
Mo gb'eke yan
Ẹba mi wa, ẹba mi wa eh
Ẹba mi wa (eh oh)
Ẹba mi wa wa o (ehn)
Ẹba mi wa (eh oh)
Ẹba mi wa wa o
Bo s'ake ni (eh oh)
Ẹba mi wa wa o
Bo s'ebọn ni (ehn oh)
Ẹba mi wa wa o ehn
Iwosi to gbe ko mi ti pọju
Irẹjẹ to gbe ko mi ti pọju
Irẹjẹ to gbe wọ mi ti pọju
Arinfin to gbe ko mi ti pọju
Bo s'ake ni eh oh
Ẹba mi wa wa o ehn
Mọ gbọ, mọ gbọ bi wọn si wi
Mọ gbọ bi wọn se n sọ, mọ gbọ
Mọ gbọ, mọ gbọ bi wọn si wi
Mọ gbọ bi wọn se n sọ, mọ gbọ, mọ gbọ
Mọ gbọ, mọ gbọ, mọ gbọ
Esu lo se driver to pa mi l'aja o
Esu lo se driver to pa mi l'aja
Esu lo se driver to pa mi l'aja o
Esu lo se driver to pa mi l'aja
Aja to ti n po ya funmi o
Wa ya keji kama f'ewu ya o
Esu lo se driver to pa mi l'aja o
Bo s'ake ni eh oh
Ẹba mi wa wa o ehn
Ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa wa o eh eh
Ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa
Iwosi to gbe ko mi ti pọju
Irẹjẹ to gbe ko mi ti pọju ah
Iwosi to gbe ko mi ti pọju eh
K'ẹru rẹ ko ma lọ le o
K'ẹru rẹ ko ma lọ le o



Writer(s): Anikulapo Kuti Fela


Fela Kuti - London Scene
Album London Scene
date of release
01-09-2009




Attention! Feel free to leave feedback.