Fela Kuti - Ololufe Mi Lyrics

Lyrics Ololufe Mi - Fela Kuti




Ololufemi, ti e ni mo fe
Alayanfemi, ti e ni mo fe
Ololufemi
Mi o se ti won mo
Alayanfemi, ti e ni mo fe
Wa fenu ko mi lenu oooohooo
Wa fara ro mi lara o
Hey hey hey hey hey
Alayanfemi, ti e ni mo fe
Ololufemi, ti e ni mo fe
Alayanfemi
Mi o se ti won mo
Alayanfemi, ti e ni mo fe
Wa fenu ko mi lenu
Wa fara ro mi lara o



Writer(s): Fela Anikulapo Kuti


Attention! Feel free to leave feedback.
//}