J.I. - Ife Mi Lyrics

Lyrics Ife Mi - J.I.



Ololufe mi ooo
Ani mo feran re
Ololufe mi ooo
Ani moferan re
Ife tolorun yonu si
Dandan ni kose
Ife see pataki
Oro Ife le o oshe koko
Ololufe mi ooo
Ani moferan re
Baby
Ololufe mi ooo
Femi dokan re
Mofe ooo(2*)
Femi denu denu
Femi to dodo
Oro Ife see pataki Oro Ife le o she koko
Ololufe mi ooo
Femi do kan re
Beat?!!!!!!
Ololufe
Mashe gbo telegan oo ololufe mi
Magbo telegan rara
Jowo mashe gbo telegan oo ololufe mi
Akinju laye ile aye le, ile aye le
Eniyan o ma feni foro afori eni
Afori eni
Mashe gbo telegan oo ololufe mi
Ololufe
Mafinu re han Omo eniyan ololufe mi
Moti gbo ooo
Mafinu re han Omo eniyan ololufe mi
AAAAAAA
Bogiri olanu Alangba o le debe ooo
Kole debe ooo
Eniyan o mafe ni to sunwon mo laye ooo
Ani mo moyen
Mafinu re han Omo eniyan ololufe mi
BEAT!!!!!!!!!!!
Awon tolorun sopo aye e mayawon
Aye emayawon ooo
Awon tolorun sopo aye e mayawon
Ema yawon oooo
Ohun toluwa bako dandan ni kose
Dandan ni kose
Ife se pataki Oro Ife le o oshe koko




J.I. - Dreams Don't Die
Album Dreams Don't Die
date of release
30-06-2013




Attention! Feel free to leave feedback.