King Sunny Ade - Sunny Koni Ku - translation of the lyrics into French

Lyrics and translation King Sunny Ade - Sunny Koni Ku




Sunny Koni Ku
Sunny Koni Ku
Koni ku o
Koni ku o
Rọmọla Ofeṣe
Rọmọla Ofeṣe
Koni ku o
Koni ku o
Sunny mi o ni ku o
Sunny mi o ni ku o
Rọmọla Ofeṣe
Rọmọla Ofeṣe
Koni ku o
Koni ku o
Tori gunugun kii ku s′ewe
Tori gunugun kii ku s′ewe
O ṣe'wọ o
O ṣe'wọ o
Ẹnikan ki ba alágẹmọ labẹ ewe
Ẹnikan ki ba alágẹmọ labẹ ewe
Bẹẹni, a ma rọ gidigba la lẹ odo
Bẹẹni, a ma rọ gidigba la lẹ odo
Koni ku sẹ
Koni ku sẹ
Rọmọla Ofeṣe
Rọmọla Ofeṣe
Koni ku o
Koni ku o
Adìyẹ yo, adìyẹ pogun
Adìyẹ yo, adìyẹ pogun
Wan l′adiye ro p'ọmọ rẹ
Wan l′adiye ro p'ọmọ rẹ
Adìyẹ rọgbọn, adìyẹ pọgbọn
Adìyẹ rọgbọn, adìyẹ pọgbọn
Wan l'adiye ro p′ọmọ rẹ
Wan l'adiye ro p′ọmọ rẹ
Wan binu gb′adiyẹ ta
Wan binu gb′adiyẹ ta
Wan f'owo ra′wo
Wan f'owo ra′wo
Awo y'ẹyin mẹfa
Awo y'ẹyin mẹfa
O fi pa kan ṣoṣo
O fi pa kan ṣoṣo
Ọkan ṣoṣo girogiro
Ọkan ṣoṣo girogiro
Ọkan ṣoṣo l′ẹrin n ṣe gbo
Ọkan ṣoṣo l′ẹrin n ṣe gbo
Ọkan ṣoṣo r'ẹfan ni sọdan
Ọkan ṣoṣo r'ẹfan ni sọdan
Ọkan ṣoṣo l′ajanaku nimi gbo kiji-kiji-kiji
Ọkan ṣoṣo l′ajanaku nimi gbo kiji-kiji-kiji
Awa ti b'egun ja o
Awa ti b'egun ja o
Aṣẹgun re'gungun
Aṣẹgun re'gungun
Ati b′ọrìṣà o
Ati b′ọrìṣà o
Awa d′oriṣa kunlẹ bọ
Awa d′oriṣa kunlẹ bọ
Awọn agbejọ ra lo f'ọlọrun ọba
Awọn agbejọ ra lo f'ọlọrun ọba
Bambaa ni baba n da
Bambaa ni baba n da
Ẹni t′ọlọrun ba ti
Ẹni t′ọlọrun ba ti
Ko ṣe f'arawe
Ko ṣe f'arawe
Ko ṣe f′arawe
Ko ṣe f′arawe
Bamba ni n baba da wa o
Bamba ni n baba da wa o
Ko ṣe f'arawe
Ko ṣe f'arawe
Ẹni Ọlọrun ba ti n nkọ
Ẹni Ọlọrun ba ti n nkọ
Ko ṣe f′arawe
Ko ṣe f′arawe
Gbamugbamu jigijigi
Gbamugbamu jigijigi
Ko ṣe f'arawe
Ko ṣe f'arawe





Writer(s): King Sunny Adé


Attention! Feel free to leave feedback.