King Sunny Ade - Ejire Ara Isokun Lyrics

Lyrics Ejire Ara Isokun - King Sunny Ade



Ejiré ara Isokun omo Edunjobi
Bin bi ejiré o inu mi a dun o
Bin bi ejiré o inu mi a dun o
Eru o ba mi o, Rara o rara o
Aya o fo mi o, lati bi ejiré
Ejiré dara, mo ni epo nile
Mo ni ẹwà l′ọna o
Taiyelolu ijo ijo
Ejire ijo o
Tin ba bi ejire mbá jo
Ijo ejiré ijo o
Mbá bi ejire mbá yo dandan
Ijo ejiré ìjọ o
Owo ile alakisa oso alakisa di Alaso
Ijo ejiré ijo o
Owo ile alakisa oso alakisa di Alaso
Ijo ejiré ijo o
Owo ile olomo meji, o so do olomo meji di olomo merin
Ijo ejiré ijo o
Omo meji jo ijo re
Ijo ejiré ijo o



Writer(s): King Sunny Adé


King Sunny Ade - Classics, Vol. 2: Ekilo Fomo Ode & the Way Forward




Attention! Feel free to leave feedback.