Niniola - Maradona Lyrics

Lyrics Maradona - Niniola



Really
Nini dey o
Shey footballer ni e, to n gba balli kiri?
Shey telescope ni e, to n wo omo kiri?
To'ju re ba fo o, don't blame it on Nini
To ba wa di l'ale, you come to me within
Ooo ni ki n la'tan, o ni maa la'tan
Ooo ni ki n d'oju mi, o lo maa la pa
Ooo ni ki n la'tan, o ni maa la'tan
Ooo ni ki n d'oju mi, o lo maa kan pa!
O maradona, oo maradona, maradona mi
O maradona, oo maradona, maradona mi
Maradooona!
Don't be wicked, die for you
If I die for you all is in vain
Wicked, die for you
If I die for you all is in vain
Ki ni mo shey fun e?
Will I satisfy you?
All my friends you have de be
Will I satisfy you?
Ooo ni ki n la'tan, o ni maa la'tan
Ooo ni ki n d'oju mi, o lo maa la pa
Ooo ni ki n la'tan, o ni maa la'tan
Ooo ni ki n d'oju mi, o lo maa kan pa!
(Maradonaaaa... don't you know that) O maradona, oo maradona, maradona mi
O maradona, oo maradona, (do-do-do-do-do) maradona mi
O maradona, oo maradona, don't maradona me
O maradona, oo maradona, don't maradona me
(Maradonaaaa... don't you know that... Marado... do-do-do-do)



Writer(s): Niniola Apata, Osabuohien Osaretin


Niniola - Maradona
Album Maradona
date of release
21-02-2017





Attention! Feel free to leave feedback.