Niyola - My Prayer Lyrics

Lyrics My Prayer - Niyola



Odun lọ òpin oh
Oh Lord Guide me
Lord guide me
Eeeh eh yeah
Ọdún lọ òpin oooh
Baba mimo
Fi ìsò rẹ sọ
ọmọ mọ
Owun yọ lekun ooh
ọdún tún tún
Majeki ó sele bàbà rere
Àṣẹ mo dùn oooh
Àdúrà gbà ṣe àmín oooh
Olúwa sọ
fi owun rere kemi
Ṣí kéré,
Ọdún lọ òpin oooh
Baba mimo
Fi ìsò rẹ sọ
ọmọ mọ
Owun yọ lekun ooh
ọdún tún tún
Majeki ó sele bàbà rere
Májẹ owó leri sunkún
Májẹ fi aṣọ òfo bora
Ogun ro ju je ro ju
Màmá je ki oje tèmi
Lafiha pípé ni mo fe
Fi mi lore
Je ń hàn
Je lọ
Baba wa se mi lógo
Dabo Ọlọ'run mi
Dabo
Dabo Ọlọ'run mi
Dabo
Màmá je ki wan fi irẹ temi pín
Màmá je ki oro mi òfo ni ọdọ Rẹ Olúwa
Dabo Ọlọ'run mi dabo
Nínú ọdún titun irẹ gbogbo ni tomiwa ooh
Nínú ọdún titun ibi gbogbo yàgò fún wa
Everything I do make God win oooh
In this new year this is my prayer
Ọdún lọ òpin oooh
Baba rere
Fi ìsò rẹ sọ
Olú ọrùn
Owun yọ lekun ooh
ọdún tún tún
Majeki ó sele bàbà rere
Eeeh eeh eh Eeeh yeah
Oooh oooooh ooh oh oooh oh
Ọdún ọdún a yabo
Ọdún ọdún a mi gidi
Peregede ni a yẹ
Peregede ni a yẹ
Peregede ni a yẹ Eeeh
Peregede ni a yẹ Eeeh eh
Odun ọdún
Ọdún ooh
A mi gidi
Peregede ni a yẹ
Àmín (this is my prayer)
Àmín (say Amen)
Àdúrà mo gbà ṣe àmín oooh
Àmín... Ase
Àmín... E se àmín oooh




Niyola - My Prayer
Album My Prayer
date of release
10-02-2017




Attention! Feel free to leave feedback.