Lyrics Bodija - Oritsefemi
MSN
gang
If
you're
still
sitting
down
you're
on
a
long
last
thing
Je
n
mọn
je
n
mo
igboro
lawa
Je
n
mọn
je
n
mo
igboro
loba
Óo
sì
ní
Bódìjà,
woss
Eko
lowa
Óo
sì
ní
Bódìjà,
wobi
Eko
non
pebi
Óo
sì
ní
Bódìjà,
Eko
lowa
Óo
sì
ní
Bódìjà,
wobi
Eko
non
pebi
Woss
woss
wobi
Toba
lo
se
laulau,
wa
gbo
paupau
Awon
eleyi
n
jeyan
oga
ni
o
Àwọn
ọmọ
idi-amin
Yé.
e
wode,
to
fe
lo
s'ede
lo
shako
ogede
Kilowade
to
wa
lon
repete
Tode
fema
se
bi
awọn
ọmọ
elemerewasa
O
d'eko
o
moyan
o,
owa
lon
shey
bi
ọmọ
to
muyan
O
d'eko
o
moyan
o,
owa
lon
shey
bi
ọmọ
to
muyan
O
d'eko
o
m'eyo
o,
o
tun
wa
lon
bawon
jiyan
O
d'eko
o
m'eyo
o,
o
lon
bawon
jiyan
Won
a
gba
e,
mí
o
gbọ
Won
a
la
e,
won
ma
da
werepe
sori
e,
won
a
tun
lo
se
golobo
lori
e
Won
a
la
e,
won
a
run
e
Oya
nah
Igboro
o
feyin,
igboro
igboro
igboro
o
feyin
Igboro
na
boss
Igboro
l'oga
Igboro
laye
n
bẹ
o,
igboro
lawa
Igboro
na
boss
Igboro
l'oga
Igboro
lota
n
bẹ
o,
igboro
lawa
Óo
sì
ní
Bódìjà,
woss
Eko
lowa
Óo
sì
ní
Bódìjà,
wobi
Eko
non
pebi
Óo
sì
ní
Bódìjà,
woss
Eko
lowa
Óo
sì
ní
Bódìjà,
wobi
Eko
non
pebi
Gba
phone
e
mu,
moni
o
gba
phone
e
mu
Malo
je
k'awon
omo
oloore
gba
phone
e
mu
Kan
to
ja
e
si,
o
ye
ko
ti
jara
é
Ma
lo
sun
awon
omo
to
ti
bu
nkan
mu
o
Ihahin
na
Lagos,
no
come
here
come
dey
form
boss
Wetin
dey
your
pocket
go
fit
loss,
omo
as
you
dey
dance
make
you
focus
D'apo
e
mu,
a
ni
ko
d'apo
e
mu
D'apo
e
mu,
a
ti
ni
ko
d'apo
e
mu
O
d'eko
o
moyan
o,
owa
lon
shey
bi
ọmọ
to
muyan
Omugo
O
d'eko
o
moyan
o,
owa
lon
shey
bi
ọmọ
to
muyan
O
d'eko
o
m'eyo
o,
o
tun
wa
lon
bawon
jiyan
O
d'eko
o
m'eyo
o,
o
lon
bawon
jiyan
Won
a
gba
e,
mí
o
gbọ
Won
a
la
e,
won
ma
da
werepe
sori
e,
won
a
tun
lo
se
golobo
lori
e
Won
a
la
e,
won
a
run
e
Igboro
o
feyin,
igboro
igboro
igboro
o
feyin
Igboro
na
boss
Igboro
l'oga
Igboro
laye
n
bẹ
o,
igboro
lawa
Igboro
na
boss
Igboro
l'oga
Igboro
lota
n
bẹ
o,
igboro
lawa
Oya
na
jenmon
Prince
Kazeem
Eletu,
Eletu
o
dibo
Zabata.
IPB
Dende
Otunba
Cashmoney
Instabul
Connect
Jenmon
jenmon
1 Life.
2 Kiss a Bride
3 Wonder
4 Unity
5 Obone Tara Bote
6 Yeye Rowling
7 Blessings
8 Pum Pum Nice
9 Ireti
10 Laye
11 Our Government I Beg
12 Slow Slow
13 Ire
14 Bodija
Attention! Feel free to leave feedback.