Lyrics Kirakita - Oriyomi Kehinde
Jerryson
production
MashaAllah
Jeko
dara
funmi
o,
kinma
w'aye
inira
K'eda
sise
bi
erin,
je
ije
eliri
Kìràkìtà
mi
lotunlosi,
je
koja
sire
Oba
maje
r'idamu,
kin
mase
w'aye
alaye
Jeko
dara
funmi
o,
kinma
w'aye
inira
K'eda
sise
bi
erin,
je
ije
eliri
Kìràkìtà
mi
lotunlosi,
je
koja
sire
Oba
maje
r'idamu,
kin
mase
w'aye
alaye
Mo
koseri
doju
ami,
mosi
gbominira
Igba
tao
r'owo
gba
shop,
oju
rito
o
laye
Anforiro
t'ifarada
pe
toba
pe
o
boya
P'ori
ton
suffer
apada
wa
d'ori
olola
Olohun
o
dojutimi,
o
funmi
lona
miran
Ofise
orin
damilola,
koma
tun
funmi
lasan
O
semi
ni
arisami
t'aye
nri
tonfola
ke
Kon
to
p'akoko
tabikeji,
won
a
'oriyomi
sha
Kìràkìtà
mi
lotunlosi
oba
oluwa,
lofi
demilade
Kìràkìtà
mi
lotunlosi,
oba
oluwa
lofi
demilde
Jeko
dara
funmi
o,
kinma
w'aye
inira
K'eda
sise
bi
erin,
je
ije
eliri
Kìràkìtà
mi
lotunlosi,
je
koja
sire
Oba
maje
r'idamu,
kin
mase
w'aye
alaye
Bee
Loju
olowo
oledabi,
bi
pawon
logbon
Loju
talika
yio
maro
polowo
je
tete
Etò
l'olohun
fisoro
yi
k'aye
le
segbe
Gbogbo
eni
tonfori
ro
kosikosi
o
laye
Olohun
a
sina
yio
pada
da
loju
emi
won
Jeko
dara
funmi
o,
kinma
w'aye
inira
K'eda
sise
bi
erin,
je
ije
eliri
Kìràkìtà
mi
lotunlosi,
je
koja
sire
Oba
maje
r'idamu,
kin
mase
w'aye
alaye
Gateman
to
ns'olode
ati
wole
olowo
Nigba
tio
i
rise
yen,
ogbon
kobosi
londa
Nigba
tobosi
opada
di
gateman
olowo
Ori
b'olowo
se
nfayo
je
aye
olola
O
wa
nsadua
k'olohun
soun
naa
lolowo
T'adua
tonse
bapada
gba
toba
d'olola
Selomi
ko
nio
pada
ma
sole
olowo?
B'aye
seri
leriyen
eto
Olohun
loje
Ise
tenikan
sowipe
ko
kamo
to
tesiwaju
Ope
lomaje
felomi
toba
rise
yen
gbamu
Jeko
dara
funmi
o,
kinma
w'aye
inira
K'eda
sise
bi
erin,
je
ije
eliri
Kìràkìtà
mi
lotunlosi,
je
koja
sire
Oba
maje
r'idamu,
kin
mase
w'aye
alaye
Aseda
mafimi
sile
seun
taye
mi
nfe
Kinma
d'iwole
kinto
pada
gba
oore
timo
nwa
At'iwe
timo
tun
rika,
je
nrola
fi
muwa
Kinma
fogbon
pelu
idea
mi
gbaye
inira
Oba
je
k'aye
fise
mi
lomi,
tola
finde
K'atiga
layemi
madeti,
maje
kole
nira
Imo
atoye
topeye
wumi
kin
r'aye
gbe
Isoro
masomi
d'ode
nibi
tobaye
fogbon
Jeko
dara
funmi
o,
kinma
w'aye
inira
K'eda
sise
bi
erin,
je
ije
eliri
Kìràkìtà
mi
lotunlosi,
je
koja
sire
Oba
maje
r'idamu,
kin
mase
w'aye
alaye
Aoni
damu
kato
lowo
lowo
Ise
kekere
owo
nla
ni
kabawon
se
Ise
kekere
owo
nla
ni
kabawon
se
Katodeni
tayenfe
isenla
lase
Katodeni
tayenfe
isenla
lase
Ibi
tegbe
wa
tin
nawo
kama
na
tiwa
Ibi
tegbe
wa
tin
nawo
kama
na
tiwa
Gbogbo
wa
laojo
lowolowo
Gbogbo
wa
laoma
kolemole
Gbogbo
wa
laoma
ni
lari
Aoni
damu
kato
lowo
lowo
Ise
kekere
owo
nla
ni
kabawon
se
Ise
kekere
owo
nla
ni
kabawon
se
Katodeni
tayenfe
isenla
lase
Katodeni
tayenfe
isenla
lase
Ibi
tegbe
wa
tin
nawo
kama
na
tiwa
Ibi
tegbe
wa
tin
nawo
kama
na
tiwa
Agbara
lola
tonije
maje
ko
dole
Maje
kosaini
maje
ko
toshi
Ike
ti
koranti
bere
kobanfun
Ola
ti
koranti
bere
kobanfun
Aponle
to
ntowo
re
làwã
bangbe
fun
Agbara
lola
tonije
maje
ko
dole
Maje
kosaini
maje
ko
toshi
Ike
ti
koranti
bere
kobanfun
Ola
ti
koranti
bere
kobanfun
Aponle
to
ntowo
re
làwã
bangbe
fun
Hajji
lateef
olumegbon
alakanni
mi
Olanrewaju
amuludun
accra
ghana
Olumegbon
ntoju
mi
fun
t'owo
t'ola
On
gbiyanju
k'aye
timowa
rorun
Bose
nfife
hanmi
malo
nfowo
momi
Amuludun
gbogbo
accra
ni
ghana
Ola
ti
koranti
bere
kobanfun
Aponle
to
ntowo
re
lawa,
bangbe
fun
Agbara
lola
tonije
maje
ko
dole
Maje
kosaini
maje
ko
toshi
Ike
ti
koranti
bere
kobanfun
Ola
ti
koranti
bere
kobanfun
Aponle
to
ntowo
re
làwã
bangbe
fun
Olohun
tunbo
ke
latifu
bose
ngbero
Koje
kola
e
tunbo
fe
dori
omo
Toripe
lojumo
nimo
nsadua
fun
At'adua
topo
eniyn
nse
fun
Tiru
e
balo
pe
mefa
laye
mi,
dangote
afe
bami
sore
ni
dandan
Olanrewaju
akanni
maje
owo
e
lo
Kawa
tanje
ninu
e
le
gbadun
si
Ike
ti
koranti
bere
k'olohun
fun
Ola
ti
koranti
bere
k'olohun
fun
Aponle
to
ntowo
re
làwã
bangbe
fun
Agbara
lola
tonije
maje
ko
dole
Maje
kosaini
maje
ko
toshi
Ike
ti
koranti
bere
kobanfun
Ola
ti
koranti
bere
kobanfun
Aponle
to
ntowo
re
làwã
bangbe
fun
Ha,
olanrewaju
da
pupo
Aye
ngba
fun
e
Oko
mosunmola
big
hajjia,
summaiyah
Oko
abebi
aliyah,
queen
of
queens
Baba
yetunde
baba
mariam
Baba
olansile
baba
kolayemi,
ese
gan
Al'olumegbon
da
pupo,
aye
ngba
fun
e
Mofeyale
rashidi
amole
jeje
Dandan
ni
kinyale
rashidi
amole
jeje
Baba
onile
tuntun
rashidi
amole
jeje
Ilenla
to
koyen
o
mani
jona
Eyi
to
tiko
tele
o
mani
wo
lai
Eyi
to
tunku
tomako
o
mani
nira
Ha,
omotosho
rashidi
amole
jeje
Meter
meter
lowomi
oteyi
mo
moore
Olohun
ma
gba
alafia
ara
amole
Olohun
mafi
towa
lenu
wo
ko
funwa
tan
Amole
o
seni
laàbò
odidi
ni
Jejelayegba
oko
basira,
oko
shukura
Oko
fatima
(alase
jeje
haulage
ebudola)
Bami
k'alhaji
ibrahima
ishola
popoola
Oko
anifa
oko
maria,
baba
afusa
baba
amira
Oni
maf'amole
towa
lenu
wo
ko
funwa
tan
Amole
o
seni
laàbò
odidi
ni
Bo
l'olawale
maso
p'òleyan,
yusufu
omo
olaegbe
da
o
Atiwa
atise
yusufu
lo
sunwon
Eniyan
lomo
olaegbe
sha
Gbogbo
iwa
e
malo
temilorun
Baba
ilyas
baba
zainab
Baba
Khalid
baba
oni
maleek
Olaegbe
sore
mawobe,
o
sore
Olawale
jeni
togbayi,
o
sore
Ha,
toripe
rere
malo
nf'ojo
aye
e
se
Aye
nroyin
e
yusufu,
wipe
oseniyan
gan
ni
Saraa
lon
fojo
aye
e
se
Aye
nroyin
e
lawale,
wipe
oseniyan
gan
ni
Eniyan
toba
nioma
sore
Ojeya
tete
sun
kuro,
fawon
ton
dena
oore
Eniyan
tobani
omale
sore
Ojeya
tete
sun
kuro,
fawon
ton
dena
oore
Yusufu
o
tun
wani
sore
Kotun
wa
gaba
lori
e,
konireti
ope
mo
Olohun
onije
omale
sore
Toriyen
ma
lola
nwo,
tiofile
jola
o
tan
Ore
oni
gbowo
e
kodiiiiii
bi
o
Ore
o
ni
gbowo
e
ko
dibi
Tor'aniyan
toma
nlo,
tonitoni
ma
lonmo
Mo
l'onilenla
moleniyan
toga
Moleniyan
toga
Abbey
de
don,
abbey
de
don,
onilenla
Prince
abiodun
nilu
germany,
onilelenla
Alhaji
alafe
qomarudeen,
onilenla
Baba
saida
baba
gbolahan,
onilenla
O
loke
timo
gbero
lati
fo,
ma
debe
Oun
tobagba
lama
fun,
ma
debe
Ao
kan
nikoja
aye
wani,
ma
debe
Oloke
tingbero
lati
fo
Maa
debe
Moki
saheed
omo
olayode
Olatunde
oko
ejire
amina
Alase
olateed
olaoluwa,
baba
olamiposi
jamal
mi
Baba
ayomide
azeezah
mi
Baba
korede
mi
adigun
Mentioning
the
names
of
die
hard
fans
Fun
publicity
won
ngbiyanju
o
Hajji
rashidi
akanmu
agba
Omo
bakare
akanmu
agunwa
Alase
gloryland
daddy
mi
agunwa
Alhaji
nurudeen
rereloluwa
Do
good
adedunmoye
mi
Adisa
oko
alhaja
abiba,
oko
alhaja
nasiro
Alase
ademola
oba
estate
Ema
ku
itoju
mi
oriyomi
Alhaji
riliwan
cooler
olori
Oloriodo
leni
timowi
Oloriodo
ijora
kingdom
Hajja
rofia
obadara
mi
Ara99
tonje
arike,
mama
shubomi
alaniade
Artist
manager
mi
oriyomi
Innocent
ahmed
ayesoro
Manager
mi
baba
adulrahman
Baba
basit
baba
aliyah
mi
Moki
ismaila
adisa
ade
Ayomide
emir
1
Moki
owolabi
mi
anisere
Lookman
baba
faoziyah
Baba
aliameen
baba
awwal
Jerryson
production
to
tatata
Pelu
hajji
qubar
engineer
mi,
ese
O
loke
timo
gbero
lati
fo,
ma
debe
Oun
tobagba
lama
fun,
ma
debe
Ao
kan
nikoja
aye
wani,
ma
debe
Oloke
tingbero
lati
fo
Maa
debe

Attention! Feel free to leave feedback.