Qdot - BREAKFAST Lyrics

Lyrics BREAKFAST - Qdot



(Lilu)
Alagbe (Shocker lo she beat)
Onilu yi joor oo
Omo eluku medemede, imole afeleja
Emi nani, omo-omo Moriamo
Qdot lo'ru ko mi
Woni oro dakun ma soko, eje nso towo mi na
Edakun, nibo lo wa, nigba ti mo foju wina?
Mo badi, imole ni mi
Oyinbo oodun lenu mi, to'ri Ibile ni mi
Te ba ni ke mu eni afiola
Labalaba to sere egun, aso re m'afaya
I'm here for the money, not the fame
Ask about me, I'm making money in the game
B'olo gini ba gun ori aja, ari le aroloko
Fuck anybody fuckable, I don't care
Mo da bi Messi, mo da bi C'Ronaldo
Mo mo Sanwo Ayanlu, eruku mo ba to
Lalude gan o'le pa Abija
Omo Ibadan to fi ewe senu, so'le Bodija?
Etakete, beri mi ni orita Molete, emi ko le ma Challengi
Moda, (moda gan)
Ata ni mi, mota (mota gan)
Ina mi o me ni to da, werepe ni mi, ema loja
(Alagbe soro)
Awardi onigi, ina igi lama fi da
Fuck your lyrics he's on the road, I'm the best
Taba ti ada, fun awon tiwa won oda
Woni won ogbomi, speaker won ni oda
Mi o needi akaba, kin to ga to alaga
Ka dobale fun ara, iyen o ni kama ga
Punchline fo won lenu lo gba-gba-gba
Ese May Weather mo gbewa
Dakun ma lo faya gba
Ayangba dangerous
Makinde pawo ju Linda Ikeji lo
Eema pa ohun ma gogo, eje n polongo
Esu lo lorita, Oluweri lo lodo
Don't near me, I'm bad
Omo ake nigbo, keru ba ara ona
Omo ma jegi je eniyan, oriki Baba mi ni
Oka mi lara gan, o'sho ju Abu Abel
Shebi ka rin kapo, yiye ni yeni
Ko de ni ye yin, ewure lo ma gba ogo yin
Boku owo kan adan, adan ma fi rogi
Kole buru titi, ki omo alapata mi wa jegi
Won wipe mariwo lari, pe'egun nbo
Nigba te'gun ri wa gan, egun gbon
Edakun, se'eiye adan ni abi eiye guungun?
Woni awon me'eiye no lapo, eiye tun ti ku
Ba ran ni'se eru, ama fi tomo je
Baba lawo ti o ja, loma pada toro je
Bi ise kan o lomo, ise kan lonlo
Ti o ba jawo wo lo ri dating, gbe sori PPP
Woni, Acapella re dun, iwo dakun ma fi ilu si (Shocker lo she beat)
Saladi mi, lo fe bami fi iru si
Ogun ti o je, se bi ewe e loku kan
Oba ni mi Alagbe ore bi kan kan
Kabiesi o (Kabiesi o, Kabiesi o) (yeah, who is here?)
Omo ajana



Writer(s): Fakoya Oluwadamilare, Mudashiru Olajide


Qdot - BREAKFAST - Single
Album BREAKFAST - Single
date of release
20-09-2021




Attention! Feel free to leave feedback.