Remi Aluko - Advice Lyrics

Lyrics Advice - Remi Aluko



Hmm ee... emi ni remison aluko ton pariwo nigboro
I boya thank you for this inspiration.
Igba melo lao lo laye, to min wo ewu irin,
Asiko melo lao lo laye, to min wa ile aye ma aya,
Iwo ti gbagbe wipe, ile aye ese mefa
Ogbeni lagbaja,
Iwo ni kokumo,
Iwo ni Kosoko
One day you go die.
Gbomi!
One day you die.
Iku pa agiliti to se jeje,
A beletase opolo to nbe.
Iku pa agiliti to se jeje,
A beletase opolo to n be.
No body can live long like metusela, metusela ooo.
Lets leave great like Nelson Mandela
Bibi ire ko mase f'owo ra,
Bibi ire ko mase f'owo ra,
Bibi ire ko mase f'owo raa!!!.
Gbo gbo oun to ndan ko ni wura,
Gbo gbo oun to ndan ko ni wura,
Gbo gbo oun to ndan ko ni wu,
Wu! Wu!! Wu!!! Wuu... ra ah...
Wu ra ah... ahh ahh ...!!
All that glitters are not gold
Ore mi t'eti ko gbo mi
Omo to ba n de bawi oo,
Eyi to ba gbo a wulo fun,
Eyi tio gbo o oremi,
Oun wo oko iparun lo ni
Abo oro la n so fun omo luabi o,
To ba de inu e, a d'odidi
Oremi t'eti ko gbo o,
Advice leyi oo
Fun arugbo ti omidan,
Ati okunrin ati obirin,
E teti ke gbomi
Gbo gbo wa lo bawi
O ba olorin wi oo
O ba pastor gan wi
O ba olori ijo wi oo
Olori ilu gan gan
Gbo gbo wa lo bawi
E teti ke gbo oo
Eyi tio de gbo ni
Oun wo oko iparun ni
Eyi ti ko de gbo ni
Oun wo oko iparun ni
Bibi ire ko mase f'owo ra,
Bibi ire ko mase f'owo ra,
Bibi ire ko mase f'owo raa!!!.
Gbo gbo oun to ndan ko ni wura,
Gbo gbo oun to ndan ko ni wura,
Gbo gbo oun to ndan ko ni wu,
Wu! Wu!! Wu!!! Wuu... ra ah...
Wu ra ah... ahh ahh ...!!
Till fade



Writer(s): Andrew Wansel, Warren Felder, Matt Campfield, Kehalni Parrish, Danny Klein


Remi Aluko - Real
Album Real
date of release
11-08-2018




Attention! Feel free to leave feedback.