Slimcase - LambaXtra Lyrics

Lyrics LambaXtra - Slimcase



Omi gbóná boso lọrun edie
Edie saporo zagazege zegezigi rosu
(Raka mailo, mix Benson mo loud yẹn kéverythin kon le...)
Oya gbakosun, gba koje
Gbakosun, gba koje
E se ma gbakosun (mr man) gba koje
Wọn gbakosun (file azaman) gba koje
Ọmọ to shashe dédé ń gbọ′ dede
To ń gbowó wire, gbọ' gboun side, se gbe ivy
Oun order casket, casket one casket two
Gbomo one bomo two, wọnú yara
O fe fagbo jẹun dobo, fagbo jẹun dobo, fagbo jẹun dobo
Fagbo jẹun dobo, to ń gbó fagbo jẹun dobo
Fagbo jẹun dobo, ó fagbo jẹun dobo
(Okay) fagbo jẹun dobo
Obìnrin dúdú obìnrin pupua
Obìnrin dúdú obìnrin pupua
Oloun ja ja obìnrin (Otunba lamba)
Oloun ja ja obìnrin (zege zige zego)
(Big muller) oya gba kosun (mili xo), gba koje
Gbakosun (IBD dende), gbáko je
O se ma gbakosun (ose Larry gágá), gbáko je
Wọnnì gbakosun (file azaman), gbáko je
Onílù káre, lulu mi nibadi
Onílù káre, lulu mi, lulu mi, lulu mi
Lulu mi nibadi (ehhhh) (Sunday Bankole pami)
Pátá oloso kín nisimi, ìlékè oloso kín nisimi
sen bo, lon wo, lon bo, lon wo
Ìlékè mami, furo gbọn, Ìlékè mami, furo gbọn
Eruku ganja (ezaa àá)
To ń gbó eba logbe jọ, eba lomo ton la la lọ lo
Láti bo lọ lọ, towo bo, tise bo, gbénu si, lari mo (egbee)
gbó egusi nie joor, egusi ni ti o ja
Ẹniti waja ó wan ẹni ó ja
Lọ fín pée ni, eerrm, magbo
Eba lọ ń egusi, eba ń egusi
Eba lo ′n wa shayo, elé ń olowo
Gbakosun (ọba gold), gba koje (ehhee)
Gbakosun (padi oosaa), gba koje (file)
E se maan gbakosun(spirituale), gba koje (ahhah)
Wọn gbakosun (Lanre typical), gba koje (quality leè)
Abakaka kii, ó mọ pe iwọ nìkan mọ'lẹ' gboti mi fun nau
Ọmọ iya mi, to ba ti istanbul, bami kay
Bami jide, ọtí yẹ
Dbreeze, Monarch, owó boxing, dasi won kon ma baja léni
(Azaman)




Slimcase - LambaXtra
Album LambaXtra
date of release
30-10-2019




Attention! Feel free to leave feedback.