Terry Apala feat. Musilliu Ishola - Palongo Lyrics

Lyrics Palongo - Terry Apala feat. Musilliu Ishola



Isola nígbà kan
Ta léni sọ sórín lagodo tiwa
Kosilu lagodo tiwa
Iro le fi pa, eke le fi se
Ọmọ egungunjobi
Terry Apala mo dode
So ń gbó rhythm
Ọmọ isoko ni e
Mo tún gbé jo alarabara kan o
Kan mi a jo
Kan yodi seyin o
Palongo yen
Alajo tán ah
Palongo leri yen
Ajo tadireke
Palongo yen
Attention, attention
Put on your dancing shoe
Make you dey follow me dance




Terry Apala feat. Musilliu Ishola - Palongo
Album Palongo
date of release
22-10-2017



Attention! Feel free to leave feedback.