African Children's Choir - Betelehemu paroles de chanson

paroles de chanson Betelehemu - African Children's Choir



Refrain: Betelehemu, Betelehemu, Betelehemu, Betelehemu.
Solo: Awa yi o ri Baba gbo jule.
Awa yi o ri Baba fehenti.
Awa yi o ri Baba gbo jule.
Awa yi o ri Baba fehenti.
Awa yi o ri Baba gbo jule.
Awa yi o ri Baba fehenti.
Awa yi o ri Baba gbo jule.
Awa yi o ri Baba fehenti.
Nibo labi Jesu,
Nibo lagbe bii si.
Nibo labi Jesu,
Nibo lagbe bii si.
Betelehemu ilu ara,
Nibe labi Baba o daju,
Iyin, Iyin, Iyin, nifuno.
Iyin, Iyin, Iyin, nifuno.
Adupe fun o,
Jooni, Baba olore o.
Adupe fun o,
Jooni, Baba olore o.
Iyin, fun o Baba anu, Baba toda wasi
(Refrain) + Solo + From the top



Writer(s): TRADITIONAL, JIM BRICKMAN


African Children's Choir - It Takes A Whole Village
Album It Takes A Whole Village
date de sortie
20-05-2007




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.