Asa - Oré paroles de chanson

paroles de chanson Oré - Asa



'lé mi ìwọ ọ'rẹ' àtojúbọ' onílé
'lé mi ìwọ ọ'rẹ' agbọk'ọlọ'kọ
'lé mi ìwọ ọ'rẹ' àdúgbò
'lé mi, 'lé k'ọmọ
Ọ'rẹ' mo àbúrò
Ọ'rẹ', Ọ'rẹ' mo ṣe dáradára
Ọ'rẹ' mo finú hàn
Owá o, ó mi síta
Ó ọ'rọ' àná
Eh b'ọ'rọ' àná
Don't come to my house
Iwo ọ'rẹ' èké àdúgbò
Don't come to my house
Ìwọ ọ'rẹ' adalérú
'lé mi, ìwọ ọ'rẹ' kòfẹ'nifẹ're
'lé mi o, 'lé rara
Ńṣe ni mo lọ lọ'jọ' yìí o
Ọkọ fẹ'mi
lo wá'ṣẹ' ṣe
Láwọn méjèèjì, wọ'n bẹ'rẹ' ìṣekúṣe
Wọ'n ń hùwà ọmọdé
Wọ'n ṣe ṣe wọ'n
Ó ọ'rọ' àná
Eh b'ọ'rọ' àná
Eh ọ'rọ' àná
Oh b'ọ'rọ' àná
wo ìjà lọ'jọ' yẹn
wo èrò ń tún
wo ẹ'jẹ' nílẹ'
Ah ọ'rẹ', ọ'rẹ' o, o mi síta
'lé mi oh-oh-oh
I don't wanna see you no more
'lé mi oh-oh
Tẹ' máà béèrè mi n'lé
Ah, 'lé mi oh-oh
I don't wanna see you no more
Ọ'rẹ' ìṣé bùṣe k'ọ'wọ' rẹ o-o
Èmi ò ti ẹ' pààyàn



Writer(s): Nicolas Mollard & Asa


Asa - Beautiful Imperfection
Album Beautiful Imperfection
date de sortie
12-09-2011




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.