paroles de chanson Ogo Ola (feat. Kenny Kore) - Babatunmise
Ogo
Ola
re
Aiku,
aisa,
aidibaje
Ogo
Ola
re
Ayeraye
o,
Oba
Ka
jumo
gb′oruko
Jesu
ga
(Iwo
l'oba,
Iwo
l′oba)
Ki
gbogbo
angeli
juba
re
(Iwo
l'oba,
Iwo
l'oba)
Let
the
earth
declare
your
majesty,
let
them
know
that
you
are
God
(You
are
God...)
Ki
a
dobale
fun
oga
ogo,
se′bi′wo
lo
tunmise
eh
eh
ah
Ogo
Ola
re
Aiku,
aisa,
aidibaje
Ogo
Ola
re
Ayeraye
o,
Oba
Ogo
Ola
re
Aiku,
aisa,
aidibaje
Ogo
Ola
re
Ayeraye
o,
Oba
S'eni
ki
n
maa
bo?
S′eni
ki
n
wa?
Ma
bo
bata,
bee
tie
ni
n
bo
Eyin
l'Oba
ajiki,
ajiyin,
ajiun
Eyin
l′Oba
ajibo
Eru
re
n
ba
mi
ooo
Mio
to
w'oju
re
Mio
to
k′orin
re
Mio
to
gb'Ogo
re
Mio
to
ooo
Eru
re
n
ba
mi
ooo
Eni
to
O
o
si
Eru
re
n
ba
mi
ooo
Ogo
Ola
re
Aiku,
aisa,
aidibaje
Ogo
Ola
re
Ayeraye
o,
Oba
Ogo
Ola
re
Aiku,
aisa,
aidibaje
Ogo
Ola
re
Ayeraye
o,
Oba
(Se
l'Oba
awon
oba)
Oba
awon
oba
Olorun
awon
omo
ogun
Gbingbiniki,
awuwo
ma
se
gbe
Erujeje
ti
n
m′igbo
kijikiji
Ko
i
to
ooo
Ijo
ti
mo
jo
l′ana
(ein)
Orin
ti
mo
ko
l'ana
(beeni)
Ope
ti
mo
gbe
l′ana
(yes)
Babatunmise!
(yeah)
Ko
i
to
ooooo
Ogo
Ola
re
o
Aiku,
aisa,
aidibaje
o
Ogo
Ola
re
o
Ayeraye
o,
Oba
Ogo
Ola
re
Aiku,
aisa,
aidibaje
Ogo
Ola
re
Ayeraye
o,
Oba
Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.