Brymo - Ààrẹ - traduction des paroles en anglais

Paroles et traduction Brymo - Ààrẹ




Ààrẹ
Monarch's Excursion
Ere okuta ati gilasi
Stones and glass ground to dust
Bo ṣana si, o ma ta papa
Beware, lest you tread recklessly
Ọlọpa wa o, o ma da rin wa
Our policemen, they watch over us
Oreke lẹwa jẹ'a ṣere
So we play our games of deception
Ere okuta ati gilasi
Stones and glass ground to dust
Bo ṣana si, o ma ta papa
Beware, lest you tread recklessly
Ọlọpa wa o, o ma da rin wa
Our policemen, they watch over us
Oreke lẹwa jẹ'a ṣere
So we play our games of deception
Ere okuta ati gilasi
Stones and glass ground to dust
Bo ṣana si, o ma ta papa
Beware, lest you tread recklessly
Ọlọpa wa o, o ma da rin wa
Our policemen, they watch over us
Ẹku owurọ
At dawn
Iroyin lati igboro la mu wa kan yin leti
News from the fields reached our doorstep
Wọn ni ni owurọ yii, awọn ọmọ èés!
They said this morning, my dear!
Wọn ti ja wọ'gboro
They have invaded our fields
Wọn dẹ ti n dana sun'le
They lie dormant, waiting
Wọn ti n dana s'oko
They wait for the crops
At'ọkọ ayọkẹlẹ ati i'ti o yọkẹlẹ
And the caravans and the trains that traverse
Gbogbo lọ dana sun
All have gone to sleep
gbe'le yin o
Be wary, my love
ṣọra yin o
Be vigilant, my love
pe awọn ọmọ yin s'ọdọ
Call your children to your side
Iyi ti o ba lọ s'ile iwe, k'o joko
The child who goes to school, let him stay
Ki olọọrun ki o ma ṣọ gbogbo wa o
May the Lord protect us all
Layọ ṣe
Fare thee well
Aàrẹ n bọ l'ajo
The Monarch embarks on a journey
Awọn ọmọwe taku s'ọrun l'aafin
Sages gaze from the heavens at the palace
Awọn ọjẹlu duro ṣigidi ọkọ ofurufu
Servants stand guard at the planes
Emi baba ọba, mo duro ṣigidi
I, the king's father, stand sentinel
Ori mi lo gbe mi k'ore
My crown elevates me to honor
Aàrẹ n bọ l'ajo
The Monarch embarks on a journey
Awọn ọmọwe taku s'ọrun l'aafin
Sages gaze from the heavens at the palace
Awọn ọjẹlu duro ṣigidi ọkọ ofurufu
Servants stand guard at the planes
Emi baba ọba, mo duro ṣigidi
I, the king's father, stand sentinel
Ori mi lo gbe mi k'ore
My crown elevates me to honor






Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.