Brymo - Ọkùnrin Mẹ́ta (Ẹ̀dùn Ọkàn) paroles de chanson

paroles de chanson Ọkùnrin Mẹ́ta (Ẹ̀dùn Ọkàn) - Brymo



Gbémi ṣán lẹ̀
mi sí′ta
Fàmí lẹ'wù ya
Tẹ̀mí lọ́rùn pa
Ènìyàn lásán ni mo jẹ́
Mo fú′yẹ́ bíi paper
Ìjí lódò
Ó gbémi lọ sóko
Ẹ̀dùn ọkàn
Òhun l'ọkọ̀
Gbé mi lọ síbi kàn
Ògá ògá ò
Ọlọ'ọ′pá gba rìbá kàsà
Ẹ̀dùn ọkàn
Òhun l′ọkọ̀
Gbé mi lọ ibi ń lọ
Ẹ̀dùn ọkàn
Fún mi lọ́kàn
Ọkùnrin mẹ́ta dé'bi ń lọ
Èmi ni ìmọ́lẹ̀
O ló′kùnkùn wọ gbó lọ
Mo á lẹ́'wù ya
Mo tẹ̀ l′ọ́rùn pa
Ènìyàn lásán mi ò jẹ́
Mo wíwo ẹ̀san
Èmi ni ìjì l'ódò
gb′ọba wọn lọ s'óko
Ẹ̀dùn ọkàn
Òhun l'ọkọ̀
Gbé mi lọ síbi kàn
Ògá ògá ò
Ọlọ′ọ′pá gba rìbá kàsà
Ẹ̀dùn ọkàn
Òhun l'ọkọ̀
Gbé mi lọ ibi ń lọ
Ẹ̀dùn ọkàn
Fún mi lọ́kàn
Ọkùnrin mẹ́ta dé′bi ń lọ
Ẹ̀dùn ọkàn
Òhun l'ọkọ̀
Gbé mi lọ síbi kàn
Ògá ògá ò
Ọkùnrin mẹ́ta dé′bi n lọ



Writer(s): Olawale Olofo'ro


Brymo - 9: Èsan
Album 9: Èsan
date de sortie
08-09-2021




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.