Fela Kuti - Monday Morning in Lagos paroles de chanson

paroles de chanson Monday Morning in Lagos - Fela Kuti



Take four
One, two, three
Satiday l'afin ta ti baba l'eko
Ojo Sunday l'afin moti aiye
Satiday l'afin ta ti baba l'eko
Ojo Sunday l'afin moti aiye
Ojo Monday nkan tan
Gbese oni she je mo, awin oni she gba mo
Oti a won bi oju
Ojo Monday Eko oni gba-gba kugba oh
(Ojo Monday Eko oni gba-gba kugba oh)
Ojo Monday Eko oni gba-gba kugba oh
(Ojo Monday Eko oni gba-gba kugba oh)
B'ebi ba pa e bo lo gbawin, wa lo s'aaro Monday oh
(Ojo Monday Eko oni gba-gba kugba oh)
Bo ba bami fun gbese ti mo je e, maa lo s'aro Monday oh
(Ojo Monday Eko oni gba-gba kugba oh)
Bo ba bami fun gbese ti mo je e, maa lo s'aaro Monday oh
(Ojo Monday Eko oni gba-gba kugba oh)
Eko oni gba-gba kugba oh, l'aaro Monday eh
(Ojo Monday Eko oni gba-gba kugba oh)
B'ebi ba pa e bo la gbawin, wa lo s'aaro Monday oh
(Ojo Monday Eko oni gba-gba kugba oh)
Ma k'ori buruku wa bami oo, o s'aaro Monday eh
(Ojo Monday Eko oni gba-gba kugba oh)
Eko oni gba-gba kugba oh, l'aaro Monday oh
(Ojo Monday Eko oni gba-gba kugba oh)
Ojo Monday Eko oni gba-gba kugba oh
(Ojo Monday Eko oni gba-gba kugba oh)
Ojo Monday
B'ebi ba pa e bo lo gbawin, wa lo s'aaro Monday oh
Ojo Monday
B'ebi ba pa e ko lo gbawin, wa lo s'aaro Monday oh
Eko oni gba-gba kugba oh, l'aaro Monday eh
Ma k'ori buruku wa bami oo, o s'aaro Monday eh
Eko oni gba-gba kugba oh, l'aaro Monday oh
O'saaro Monday oh
Bo fe mo npa aro Monday
Lo ba oni taxi ko lo o sanwo
Won be e fa jagbon aro Monday di jagbon ale Monday
Ma k'ori buruku ba wa l'eko l'aro Monday eh
Aro Monday, eh, eh, eh, oh
Hey, eh, eh, eh, eh



Writer(s): Fela Anikulapo Kuti


Fela Kuti - He Miss Road
Album He Miss Road
date de sortie
01-09-2009




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.