King Sunny Ade - Alashe L'Aiye paroles de chanson

paroles de chanson Alashe L'Aiye - King Sunny Ade



Alase l'aiye alase lorun
Baba baba baba ku ise
Alase l'aiye alase lorun
Baba baba baba ku ise
Iyanu to'se l'aiye mi lo jo mi l'oju
Mo dupe ore ana
Mo tun dupe ore oni
Ore ti kin ye n'igbekele mi
Iyi ogo ye e o
Bo n ti se mi pelu mi
Ni ko ma se
Emi o yin oluwa
Oba rere to n sike mi
Emi o yin oluwa
Oba rere to n sike mi
Ma f'ohun mi yin baba mi ni
Ma fi jo mi yin
Ma f'ohun mi yin baba mi ni
Ma fi jo mi n yin
Ma jo roin roin
Ma jo roin roin
Ma d'ibo t'ori ile majo roin roin
Ma jo roin roin
Ma jo roin roin
Ma d'ibo t'ori ile majo roin roin
Opa ki n fa gbo gbo
Shekere oba n'ile oluwa
Shere ni o maa lo
Opa ki n fa gbo gbo
Sekere oba n'ile oluwa
Sere ni o maa lo
Oluwa lo pe mi, emi ko lo pe ra mi
Ko le baje
Ko le baje ooo
E wi ki n gbo
Ko le baje
Ko le baje ooo



Writer(s): King Sunny Ade


King Sunny Ade - E Dide (Get Up)
Album E Dide (Get Up)
date de sortie
29-07-2008




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.