King Sunny Ade feat. The Golden Mecury of Africa - Mo Ti Kole Mi Sori Apata paroles de chanson

paroles de chanson Mo Ti Kole Mi Sori Apata - King Sunny Ade




Lorí òkè calvary o
Lorí òkè calvary o
Lori igi agbelebu
Wan kan Jésù mọ'gi o
Wan tutọ lára o
Wan de ni ade ẹgún
Nitori ẹsẹ t'emi
Nitori ẹsẹ ti
B'iya ọrún ṣe pọ tó, ko dakẹ adura
O n bẹbẹ fún wa
"Baba d'áríjì wan, wan o mọ ùn wan ṣe"
Lorí òkè calvary o (Ẹni kín gbọ)
Lorí òkè calvary o
Lori igi agbelebu
Wan kan Jésù mọ'gi o
Wan tutọ lára o
Wan de ni ade ẹgún
Nitori ẹsẹ t'emi
Nitori ẹsẹ ti
B'iya ọrun ṣe pọ tó, k o dakẹ adura
O n bẹbẹ fún wa
"Baba d'áríjì wan, wan o mọ ùn wan ṣe"
Moti kọ ilé mi sori apata ayérayé
Nibi ti ibi aye ko le de
Moti kọ ilé mi sori apata ayérayé
Nibi ti ibi aye ko le de
Eyi naa lo m'ọkan mi balẹ
Eyi naa lo m'ọkan mi balẹ
Apata ayérayé ṣe ibi isadi mi
Jẹ omi owẹjẹ
Ko ṣàn lati ira rẹ
Ṣe iwosan f'ẹsẹ mi
Moti kọ ilé mi sori apata ayérayé
Nibi ti ibi aye ko le de
Moti kọ ilé mi sori apata ayérayé
Nibi ti ibi aye ko le de
Eyi naa lo m'ọkan mi balẹ
Eyi naa lo m'ọkan mi balẹ
Apata ayérayé ṣe ibi isadi mi
Jẹ omi owẹjẹ
Ko ṣàn lati ira rẹ
Ṣe iwosan f'ẹsẹ mi



Writer(s): King Sunny Ade


Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.