Mormon Tabernacle Choir - Betelehemu paroles de chanson

paroles de chanson Betelehemu - Mormon Tabernacle Choir




Betelehemu
Awa yio ri Baba gbojule
Awa yio ri Baba fehinti
Nibo labi Jesu
Nibo labe bi i
Betelehemu, ilu ara
Nibe labi Baba o daju
Iyin, iyin, iyin nifun o
Adupe fun o, adupe fun o, adupe fun ojo oni
Baba oloreo
Iyin, iyin, iyin fun o Baba anu
Baba toda wasi
Betelehemu



Writer(s): Via Olatunji, Wendell Whalum


Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.