paroles de chanson Tanadi - Oriyomi Kehinde
Jerryson
production
Tanadi
arawa,
koma
ma
da
erora
Oun
abase
loni,
bo
dola
a
yiwa
Tanadi
arawa,
koma
ma
da
erora
Oun
abase
loni,
bo
dola
a
yiwa
Naam
Oun
tomaje
ti
teni,
kole
fonida
laye
Teda
ba
nsebaje
sibi
tati
ndogbon
Pe
kebi
ma
pomo
wa
atiyawo
wa
ni
Benikan
fe
dina
atije
atatimu
wa
K'olohun
bawa
febi
atedi
se
tiwon
Kota
o
toro
je
kosi
ni
moribo
Tanadi
arawa,
koma
ma
da
erora
Oun
abase
loni,
bo
dola
a
yiwa
Nemesis
loyinbo
ma
npesan
toba
de
Eni
tonse
rere
loni
kole
gbe
laye
Koda
bonfibi
su,
yio
gbesan
toba
ya
Eni
aba
seka
fun,
kokan
miri
lasan
Esan
a
ke
dandan,
nigba
toba
ke
tan
Sereni
to
nsebi
fun
nlati
jeka
toba
ya
Tanadi
arawa,
koma
ma
da
erora
Oun
abase
loni,
bo
dola
a
yiwa
Sababi
arawa,
eyi
taba
fe
je
Kaje
si
ti
rere
laiseka
funrawa
Oun
abase
loni,
bo
dola
a
yiwa
Malaika
tonko
rere,
otun
londuro
si
Eyi
to
nko
tibi,
egbe
keji
londuro
Sapamo
kajori,
ama
wo
e
rekete
O
koja
pe
moti
ti
ilekun
mi
ni
kokoro
Tanadi
arawa,
koma
ma
da
erora
Oun
abase
loni,
bo
dola
a
yiwa
Ore
o
gbe
e
iro
lopa,
o
lowokan
ika
ninu
Bareni
tonse
rere,
ko
ma
legbe
laye
O
le
ma
jodo
eni,
to
fokansi
rarara
Ma
foju
sunbi
ore,
p'oma
gbawa
to
ba
ya
Yoruba
ntenumo,
oro
kan
won
a
wipe
Basore
fun
arara,
omiran
la
gbewa
Tanadi
arawa
Koma
ma
da
erora
Oun
abase
loni,
bo
dola
a
yiwa
Wa
semi
lakin,
fidunnu
tami
lore
Maje
nbekun
sun,
maje
nbekun
ji
Wa
semi
lakin,
fidunnu
tami
lore
Maje
nbekun
sun,
maje
nbekun
ji
Oba
mafaye
mi
sile,
kemi
nikan
o
dagbe
Loni
alo
jeun,
enikan
lo
mowo
le
Ola
alo
raso,
enikan
raso
funmi
Bonse
nsore
funmi,
jekinle
ma
se
funyan
Konma
yomi
legbe,
wa
tete
tami
lore
Ma
je
nte
lebi,
ma
yomi
lara
Wa
semi
lakin,
fidunnu
tami
lore
Maje
nbekun
sun,
maje
nbekun
ji
MashaAllah
Nigba
ti
ko
sowo,
moma
wa
lalafia
Towo
bawa
de,
ma
faisan
demi
mole
Maje
kin
foshi
mo
awon
eyan
tiwon
femi
Kaye
ma
fiku
mo
iwa
timoni
toda
Kin
se
party
rero,
kin
bale
mo
entokomije
Kin
nfowo
pelere,
ko
f'apo
shaka
k'owo
lo
Wa
semi
lakin,
fidunnu
tami
lore
Maje
nbekun
sun,
maje
nbekun
ji
Eni
to
sun
lale
ana
pelu
sadness
O
ji
loko
keji,
koma
masi
happiness
Gba
p'olohun
loba
tole
sore
express
Lo
fokan
bale.
Ko
lewa
ni
readiness
Pa
ironu
ti.
Kole
wa
ni
wellness
Tori
tola
bade,
koba
e
pelu
fitness
Wa
semi
lakin,
fidunnu
tami
lore
Maje
nbekun
sun,
maje
nbekun
ji
Bee!
Oore
ofe
lari
gba
o,
oore
ofe
lari
gba
o
Awa
naa
ko,
isesi
wa
naa
ko
lodaju,
oore
ofe
lari
gba
o
Oore
ofe
lari
gba
o,
oore
ofe
lari
gba
o
Awa
naa
ko,
isesi
wa
naa
ko
lodaju,
oore
ofe
lari
gba
o
Yaaa
robbi
Olohun
oma
ku
ise
o,
ni
gbogbo
igba
monrise
e
Nidi
isemi
mohan
nbe
o,
aga
niwaju
lo
tomi
sio
Emi
naa
ko,
isesi
mi
naa
ko
lodaju
Oore
ofe
nmori
gba
o
Oore
ofe
lari
gba
o,
oore
ofe
lari
gba
o
Awa
naa
ko,
isesi
wa
naa
ko
lodaju,
oore
ofe
lari
gba
o
Allah
Okiki
ayo
nile
wa,
ariwo
ayo
nilemi
Aanu
e
timoma
tinwa
o,
koje
nrigba
loni
o
Womise
laanu,
adua
mi
oba
je
o
gba,
oloore
ofe
ni
o,
Allah
Oore
ofe
lari
gba
o,
oore
ofe
lari
gba
o
Awa
naa
ko,
isesi
wa
naa
ko
lodaju,
oore
ofe
lari
gba
o
MashaAllah
Oba
atobiju
ma
funmi
lo,
o
kuku
timo
ma
dupe
o
Oore
totun-tosi
jenri
gba
o,
oore
tiwa
teyin
ko
bami
Maje
ko
fomi,
koma
kojaa
mi
yah
robbi
Oloore
ofe
ni
o
ooo
Oore
ofe
lari
gba
o,
oore
ofe
lari
gba
o
Awa
naa
ko,
isesi
wa
naa
ko
lodaju,
oore
ofe
lari
gba
o
Morire
gba
mo
kore,
ire
ayomi
nlekun
Emi
rire
gba
mokore,
ire
ayomi
nlekun
Moni
kin
femi
ro
ni,
loba
gbabe
ja
sope
Inumidun
mojelo,
modupe
koja
s'asan
Ma
beru
maselo,
aimoye
danwo
tonjawo
Opportunity
ojo
kan
ma
nsoni
deyan
laye
Morire
gba
mokore,
ire
ayomi
nlekun
Emi
rire
gba
mokore,
ire
ayomi
nlekun

Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.