Oyinkanade feat. Q Dot - Oluwa paroles de chanson

paroles de chanson Oluwa - Q Dot , Oyinkanade



Bopolo se nyo loju elegusi ko ku le fi jeun
Gboro mi ro baba
Kaye mama sun mije o
See everywhere I dey go people dey hail my name now
No dey walk alone like my liver polo
Mo ti rirapada
Iyanu ti sele o
Okan mi ti bale
Anyone wey try choppu na now
Mo ti rirapada o
Iyanu ti sele o
Okan mi ti bale
Anyone wey try choppu na now eee
Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved
Oluwa, Oluwa, Chineke is involved
Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved
Is involved
Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved
Oluwa, Oluwa, Chineke is involved
Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved
Is involved
Qdoti loruko mi
Won gbohun soke so nile keu
Mo seri mo da fa laafin orun
Hijira le, hijira mi sauda
Adaba ti ko le fo, omo araye lo sun da
Awon asebi n binu wa, tori awon o biru wa
Oyinkade pelu Qdoti
E ole masiri wa
Tori ewure ole gato malu
Lasma ole momo yahoo
Hijira le, hijira malaika seri bumi
Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved
Sakaburi Sakaburi
Oluwa, Oluwa, Chineke is involved
Senseburi Sadaseri nabana
Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved
Seli seli mayafuri
Is involved
Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved
Oluwa, Oluwa, Chineke is involved
Oluwa, Oluwa, Oluwa is involved
Oluwa is involved, Chineke is involved
Ole le le le
Ele le le le
Sele ole le le le
Ele le le le
Sele ole le le le o
Ele le le le
Mba ole le le le le le le o
Ele le le le
Obami atobajaye
Iwo lo n gbe leke aronipin o
Iwo lon fun mi loroso laarin egbe Baba
Oya mo ki o pe yaba yabo sha o Baba
Hey hey hey ihe hey hey yah ah



Writer(s): Oyinkanade


Oyinkanade feat. Q Dot - Oluwa
Album Oluwa
date de sortie
21-12-2017

1 Oluwa



Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.