Sheun Natural - Elédùmarè paroles de chanson

paroles de chanson Elédùmarè - Sheun Natural



Eniyan on se Elédùmarè
Say GoGo
Ninu ofii ninu ola omo Pandoro n dagba
Mo dupe Baba
Ero ota Lori mi ti dasan
Temitope Baba
Eni ta ti ro pe kole pago
N′kole alaja mefa
Mo m'ope mi wa ewa bamiyo
E k′halleluyah meta ehh
Gbogbo aye e dide
E gbohun soke
Eyin ara mi e dide
E korin soke oh
Elédùmarè
Elédùmarè
Elédùmarè
Ahhh ahh
Ahh rih ahhh
Ariba
Sese ninu mi dun
Ayo kun'nu okan mi o
Hmmm hmm
Hmm mm
Sese ninu mi dun
Ayo kun'nu okan mi oo
Ooooo
Oooh ohhh
Mayo mayo mayo
Oluwa lo se mi logo
Mayo mayo mayo
Emi gan gan l′omo ologo
Mayo mayo mayo
Emi gan gan ni GOGO
Uhhhhhh
Gbogbo aye e dide
E gbohun soke
Eyin ara mi e dide
E korin soke oh
Elédùmarè
Elédùmarè
Elédùmarè
Sheun Natural yeah
Oshey Drimz
Ninu ofii ninu ola omo Pandoro n dagba
Mo dupe Baba
Say GOGO



Writer(s): Sheun Natural


Sheun Natural - Elédùmarè
Album Elédùmarè
date de sortie
11-08-2021




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.