paroles de chanson Logan Ti O De - Tope Alabi
Emi
mo
oun
oju
mi
ti
ri
Mo
mo
oun
eti
mi
ti
gbo
Mo
mo
oun
oju
mi
ti
ri
Mo
mo
oun
eti
mi
ti
gbo
Logan
t'o
gbo
iro
ayo
re
o
Olugbala,
aye
mi
l'eto
Logan
t'o
gbo
iro
ayo
re
o
Olugbala,
aye
mi
l'eto
Mo
mo
oun
aiye
ma
ti
wi
Mo
mo
oun
eniyan
ma
ti
so
Won
ti
pe
wa
ni
agan
ri
Bo
ya
won
ti
pe
o
l'oloshi
ri
Sugbon,
Logan
t'o
de
o
Olugbala,
l'aye
mi
l'eto
Sugbon,
Logan
t'o
de
yi
o
Olugbala,
aye
e
l'eto
Aye
t'o
ti
daru
tele
tele
o-o,
Logan
ti
o
de
Oro
t'eniyan
ti
fi
s'alufaani
re,
Logan
ti
o
de
Oro
ti
ko
dara
ti
a
ti
so
si
o,
Logan
ti
o
de
Oruko
to
kii
se
ti
e
t'a
ti
pe
o,
Logan
ti
o
de
Ani,
Logan
ti
o
de
o
Olugbala,
aye
e
l'eto
Logan
ti
o
de
o
Olugbala,
aye
e
l'eto
Logan
ti
Jesu
de
Olugbala
laye
e
l'eto
Ko
s'oruko
t'aye
o
le
pe
ni
Won
a
ma
pe
ni
l'agan
l'ona
gbogbo
B'o
ba
lowo
lo
wo
agan
ni
B'o
ba
bi'mo
o
agan
ni
B'o
ba
t'egbe,
ko
d'agba,
agan
l'oje
Sugbon
Logan
ti
o
de,
so
pe,
Logan
ti
o
de
Ani,
Logan
ti
o
de
lesekese,
Logan
ti
o
de
Haaa,
Logan
ti
o
de
o
Olugbala,
l'aye
e
l'eto
Logan
ti
o
de
o
Olugbala,
l'aye
e
l'eto
Instantly
l'onje
bee,
Bo
se
n
de
bayi,
won
de
yi
oruko
pada
Eh!
Logan
ti
o
de
e-e-e
(Logan
ti
o
de)
Eni
t'a
pe
l'agan
e
ma
so
wipe
(Logan
ti
o
de)
Awon
t'a
ti
f'oruko
aburu
pe
ni
le
won
yi
(Logan
ti
o
de)
Ani,
Logan
ti
o
de
o
Olugbala
(l'aye
mi
l'eto)
A-aye
mi
l'eto,
Logan
ti
o
de
o
Olugbala
(l'aye
mi
l'eto)
Ani
e-e,
Logan
ti
o
de
o
Olugbala
(l'aye
mi
l'eto)
Ani,
Logan
ti
o
de
o
Aseda
(l'aye
mi
l'eto)
Ani,
Logan
ti
o
de
o
Olorun
o-o
(l'aye
mi
l'eto)
Irawo
owuro,
Omo
Mary,
yo
sinu
oro
mi
(l'aye
mi
l'eto)
Alagbara
ni
Shiloh
lo
ba
ranti
mi
si
rere
(l'aye
mi
l'eto)
Haa,
enu
mi
wa
kun
fun
erin
o
gbogbo
(l'aye
mi
l'eto)
Aye
mi
gba
iyipada
otun
o,
Logan
t'o
de
(l'aye
mi
l'eto)
Aye
mi
ba
l'eto
l'ota
ba
n
wo
iran
mi
(l'aye
mi
l'eto)
Aye
mi
l'eto
l'ota
ba
n
wo
iran
mi
(l'aye
mi
l'eto)
Ota
ka'wo
ro
enu
won
gbe
tan
l'ori
oju
kan
(l'aye
mi
l'eto)
Haa,
Ee,
Logan
ti
o
de
e
Olugbala
(l'aye
mi
l'eto)
Thank
You
Lord
Jesus
for
all
that
You
are
1 Imole De
2 Logan Ti O De
3 Awa gbe o ga
4 All the Glory
5 Iwo Lawa O Ma Bo
6 Kabi o osi
7 No One Else
8 Eru Re To Ba
9 Olowo Ina
10 We Have Come
11 Emi Mimo
12 Oba mi De
13 Ayo
14 War
15 Alayo
16 Adonai
17 Angeli
Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.