paroles de chanson Ta Lo Dabi Re? - Tope Alabi
Jehovah
alagbara
oba
to
tobiju,
Kabiesi
re
o
Eni
mimo
julo
ati
alaanu
julo,
hosanna
fun
oruko
re
Iwo
apata
wa
ati
ile
iso
wa,
kabiesi
re
o
Awa
juba
re
o,
awa
si
foribale,
iba
re
o,
Iba
re
o
Oluwa
talo
dabi
re
laye
lorun?,
kosio
komasi
o
Oluwa
talo
dabi
re
laye
lorun?,
kosio
komasi
o
Angeli
Won
juba
re
lojo
jo
lorun,kabiesi
re
o
Kerubu
oun
serafu
lorun
yi
ite
re
ka,
hosanna
fun
oruko
re
Ohun
lo
gbawala
lowo
isoro
gbo
gbo,
awa
yin
o
oluwa
Eni
to
kawaye
ninu
ife
to
gaju,
hosanna
si
oluwa
Oluwa
ko
seni
bi
re
laye
lorun?,
kosio
komasi
o
Oba
ogo
koseni
bi
re
laye
lorun,kosi
o
bi
re
Aye
nsa
tatan
pegan
tesu
si
un
hale,
lalai
o
orore
ayeIji
Iji
aye
banja,
to
kun
re
re
si
nrugo,
lai
lai
o
agbara
re
re
Oluwa
talo
dabi
re
laye
lorun?,
kosi
o
komasi
o)
Oluwa
o,
oluwa
o
iyin
ope
nikan
lo
ye
o
o
Oluwa
o,
oluwa
o
iyin
ope
nikan
lo
ye
o
o
Awa
niran
ti
nsaferi
re,
olorun
to
to
o,
olorun
to
po
Aseda
wa
o,
olorun
o,
awa
a
gbohun
wa
soke
si
o
A
gboju
le
o,
a
o
ni
jogun
ofo,
iwo
la
o
sin
titi
aye
wa
Oluwa
o
oluwa
o,
iyin
ope
nikan
loye
o
o
Oluwa
o
oluwa
o,
iyin
ope
nikan
loye
o
o
Awa
niran
ti
nsaferi
re,
olorun
to
to
o,
olorun
to
po
Aseda
wa
o,
olorun
o,
awa
a
gbohun
wa
soke
si
o
A
gboju
le
o,
a
o
ni
jogun
ofo,
iwo
la
o
sin
titi
aye
wa
Oluwa
talo
dabi
re
laye
lorun?,
kosio
komasi
o
Oga
ogo
koseni
bi
re
laye
lorun?,
kosio
bi
re
Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.