Wizkid feat. Wande Coal - Ololufe (feat. Wande Coal) paroles de chanson

paroles de chanson Ololufe (feat. Wande Coal) - Wizkid , Wande Coal



I can't believe that she don't
And the thing I believe go
She say W mo cold
O wa sọ pe W mi o cold o (P!)
Wanna be on your show
Wanna put me on your shoulder
O ma fàṣẹ, she can play with the wall
I dey fight you, gonna won with the wall
Layẹmi, sọ fun wọn mo nifẹ, mo nifẹ gan ni
Fine lady girl, you different, different gan ni o
I no know why but mo miss ẹ, mo miss gan ni o
Bad girl, I'm addicted, addicted gan ni o
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ (giddem!)
(Hmm, sọ fun wọn mo n'ifẹ)
(Mo ni, Fọlashade)
(Sọ fun pe mo n'ifẹ, mo n'ifẹ gan ni o)
Layẹmi, Ọlayẹmi, mo n'ifẹ
Funkẹ, sọ fun ẹ, "Mo n'ifẹ"
Titilọla, hmm, sọ fun ẹ, "Mo n'ifẹ"
Mo ni, Fọlashade
Sọ fún pe mo n'ifẹ, mo n'ife gan ni
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Ko, ko, ko, ko
Konkobilo, ko-ko-ko
Ọwá fẹ pàdé ìsàlẹ̀
Òye fún konkobilo
Ko, ko, ko, ko
Owa fẹ jẹ ko-ko-ko-ko
Mo ni ko pàdé ìsàlẹ̀
Ìyẹn gan lo ṣe ko-ko
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ (giddem!)
Layẹmi, Ọlayẹmi, mo n'ifẹ
Funkẹ, sọ fun ẹ, "Mo n'ifẹ ẹ"
Titilọla, hmm, so fun ẹ, "Mo n'ifẹ"
Mo ni, Fọlashade
Sọ fún pe mo n'ifẹ, mo n'ifẹ gan ni
Gbé mi de bẹ
Gbé mi de-, gbe-
Gbé mi de bẹ, de bẹ
Gbe-
Wọn lo wa ji (gbé mi de bẹ)
Wọn mo ji
Wọn pe mo ji
Ki ni mo de?
Ani gbé? (Gbe mi)
Wọn ni, "Ki lo wi?
Mo ni mo de
Wọn ni mi o
Mo gbéra dídé (gbe mi)
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé
Mo gbéra dídé



Writer(s): Michael Collins, Wande Ojosipe


Wizkid feat. Wande Coal - S2
Album S2
date de sortie
21-12-2023



Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.